Jump to content

Fẹ́mi Adébáyọ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Femi Adebayo)
Fẹ́mi Adébáyọ̀
Fẹ́mi Adébáyọ̀
Ọjọ́ìbíLagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian (1978-present)
Iṣẹ́
  • Actor
  • Director
  • Producer
  • Politician
  • Lawyer
Ìgbà iṣẹ́1985-present (Ogun Ajaye)
Parent(s)Adebayo Salami

Fẹ́mi Adébáyọ̀ (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkànlélọ̀gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1973) [1] jẹ́ amòfin, gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí Ìlọrin ni ìpínlẹ̀ Kwara. Bákan náà Fẹ́mi Adébáyọ̀, títí di ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 2019 jẹ́ Olùdámọ̀ràn Pàtàki lórí àṣà, ìrìn-afẹ́ àti iṣẹ́-ọ̀nà fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara àná, Abdulfatai Ahmed. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, Adébáyọ̀ Sàlámì, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ọ̀gá Bello.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]