Lagbaja
Ìrísí
Lagbaja tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Bísádé Ológundé tí a bí ní ìlú Èkó ni ọdún 1960 jẹ́ gbajúgbajà akọrin afrobeat ọmọ orílè èdè Nàìjíríà. Gbogbo ènìyàn mọ akọrin yí sí Lágbájá nítorí wípé ó jé ẹni tí ó fẹ́ràn láti máa lo ìbòjú láti dáàbò bo ara rẹ kí wọn má le dáa mọ̀.[1][2] Ó gbàgbọ́ nínú àtúntó ìlú láti ipasẹ̀ orin kíkọ.
Lagbaja | |
---|---|
Glo Oga SIM - The Unrivaled Big Boss of Data ft. Lagbaja | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Bisinuade Ologunde |
Irú orin | Afrobeat |
Occupation(s) | Singer-songwriter, instrumentalist, founder of Opatradikoncept |
Instruments | Percussion and vocals |
Years active | 1975–present |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ologunde mú orúkọ ìnagije rẹ̀ "Lagbaja" látara "Jane Doe" tí ó túnmọ̀ sí en t́ ó fi ojú rẹ̀ pamọ́. Orúkọ rẹ̀ yìih hàn nínú ìmúra rẹ̀ àti ìbòjú tó fi bojú. Ó dá ẹgbẹ́ akọ́kọ́ rẹ̀ silẹ̀ ní ọdún 1991 ní ìpínlè Èkó.[3][4]
Àmì-ẹ̀yẹ rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 2006 Channel O Music Video Awards – Best Male Video ("Never Far Away")[5]
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 'Ikira', 1993
- Lagbaja, 1993[6]
- Cest Un African Thing, 1996
- ME, 2000
- WE, 2000
- We and Me Part II, 2000
- ABAMI, 2000
- Africano... the mother of groove, 2005
- Paradise, 2009
- Sharp Sharp, 2009
- 200 Million Mumu (The Bitter Truth), 2012
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Tunde, Okanlawon. "Nigerians celebrate Iconic Afrobeat musician, Lagbaja". PM News. https://www.pmnewsnigeria.com/2020/05/20/nigerians-celebrate-iconic-afrobeat-musician-lagbaja/. Retrieved 21 June 2020.
- ↑ Mark, Jenkins. "Lagbaja takes Afropop in many different directions at Howard Theater". The Washington Post. https://www.washingtonpost.com/entertainment/music/lagbaja-takes-afropop-in-many-different-directions-at-howard-theater/2015/05/19/5b329408-fd65-11e4-8b6c-0dcce21e223d_story.html. Retrieved 21 June 2020.
- ↑ Jon, Pareles. "POP REVIEW; Mining a Musical Diaspora, From a Yoruban Beat to Jazz". The New York Times. https://www.nytimes.com/2001/08/11/arts/pop-review-mining-a-musical-diaspora-from-a-yoruban-beat-to-jazz.html?pagewanted=1. Retrieved 21 June 2020.
- ↑ Annemette, Kirkegaard (2002). Playing with Identities in Contemporary Music in Africa. pp. 32–35. ISBN 9789171064967. https://books.google.com/books?id=jlko7YMatxIC&q=lagbaja+part+with+ego&pg=PA32. Retrieved 21 June 2020.
- ↑ BBC: Channel O Spirit Of Africa Music Video Awards 2006
- ↑ "The Lagbaja Story". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2009-12-25. Retrieved 2022-03-08.