Jump to content

Kunle Afolayan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kunle Afolayan
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-30) (ọmọ ọdún 49)
Ebute Metta, Lagos State, Nàìjíríà
IbùgbéMagodo, Ikeja, Lagos State, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
Olólùfẹ́Tolu Afolayan
Àwọn ọmọ4
Parent(s)Ade Love - father
Àwọn olùbátan

Kunle Afolayan (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé, Adeyemi Afolayan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love[1] [2]

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kúnlé jẹ́ ọmọ bíbí Ìgbómìnà pọ́ńbélé láti ìpínlẹ̀ Kwara gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú. Gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò àná ni bàbá rẹ̀ Ade Love. Kúnlé kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìsúná ọ̀rọ̀-ajé. Ó ṣiṣẹ́ nílé ìfowópamọ́ fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe sinimá àgbéléwò ṣíṣe lọ́dún 2015. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti ń kópa ní ìwọ̀nba kí ó tó di àkókò yìí. Kúnlé máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa tó ṣòódó. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sìn ni àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà gẹ́gẹ́ bí eléré tíátà.[3] [4]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Film Role Notes Ref
Actor Director Producer Writer
1999 Saworoide Yes
2002 Agogo Eewo Yes
2005 Ti Ala Ba Ku Yes
2006 Irapada Yes Yes Yes Yes [5]
Èjiwòrò Yes
2007 Onitemi Yes
2009 The Figurine Yes Yes [6]
Farayola Yes
2012 Phone Swap Yes Yes Yes [7]
2014 Dazzling Mirage Yes [8]
1 October Yes Yes Yes [9]
2016 The CEO (fíìmù 2016) Yes Yes [10]
2017 The Bridge Yes Yes [11]
Omugwo Yes Yes [12]
2018 Crazy People Yes
2019 Mokalik Yes Yes [13]
Diamonds in the Sky Yes [14]
2020 Citation Yes [15][16]
2021 Ayinla Yes [17]
Swallow Yes Yes Yes Yes [18]
A Naija Christmas Yes [19]
2022 Anikulapo Yes Yes Yes
2023 Ijogbon [20] yes

Awọn àmì ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Award Category Film Result Ref
2019 Best of Nollywood Awards Director of the Year Diamond in the Sky Wọ́n pèé [14]
2021 Net Honours Most Searched Actor Wọ́n pèé [21]
2023 Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Indigenous Language – Yoruba Anikulapo Gbàá [22]
Best Movie West Africa Yàán
Best Overall Movie Gbàá
Best Director Yàán

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Kunle Afolayan Biography, History, Asset and Net Worth - Austine Media". Austine Media. 2018-05-20. Retrieved 2019-12-09. 
  2. "Kunle Afolayan". Leadership Newspaper. 2019-04-07. Retrieved 2019-12-09. 
  3. Hoad, Phil (2012-10-30). "Out of Africa: Kunle Afolayan bids to bring Nollywood cinema to the world". the Guardian. Retrieved 2019-12-09. 
  4. "BIOGRAPHY". OKIKI AFOLAYAN CONCEPTS. 2018-01-31. Archived from the original on 2019-12-09. Retrieved 2019-12-09. 
  5. "Leila Djansi's Sinking Sands Listed On CNN Among 10 Must-See African Films". news1ghana.com. Retrieved 22 October 2014. 
  6. Obenson, Tambay A. (28 October 2013). "Halloween 2013 Countdown - Nigerian Director Kunle Afolayan's Horror/Thriller 'The Figurine'". IndieWire. Shadow and Act. Archived from the original on 26 April 2014. Retrieved 25 April 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :1
  8. Nwanne Chuks (28 June 2014). "Lala Dazzles In Kelani's Dazzling Mirage". The Guardian (Nigeria). Archived from the original on 12 August 2014. Retrieved 7 August 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named CEOunveil
  11. nollywoodreinvented (13 September 2019). "The Bridge". Nollywood REinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 November 2019. 
  12. "Kunle Afolayan, Omowunmi Dada, Ayo Adesanya attend media screening". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 April 2017. Retrieved 3 November 2019. 
  13. "Movie Review: Kunle Afolayan's 'Mokalik' thrives on memory, not viewer satisfaction" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 November 2019. Retrieved 6 May 2020. 
  14. 14.0 14.1 Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-10.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  15. Augoye, Jayne (3 November 2020). "Kunle Afolayan screens 'Citation' in Lagos". Premium Times. Retrieved 7 November 2020. 
  16. Report, Agency (8 July 2022). "Kunle Afolayan's Citation wins 'Best International Film' in UK award". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 29 July 2022. 
  17. Nwogu, Precious (14 December 2020). "Tunde Kelani announces production of Ayinla Omowura biopic titled 'Ayinla'". Pulse Nigeria. Retrieved 12 May 2021. 
  18. "Swallow (2021) review – this is hard to swallow.". Ready Steady Cut. October 2021. Retrieved 2 October 2021. 
  19. Kennedy, Lisa (16 December 2021). "'A Naija Christmas' Review: Honoring a Mother's Wish - The New York Times". https://www.nytimes.com/2021/12/16/movies/a-naija-christmas-review.html. Retrieved 16 December 2021. 
  20. "Ijogbon", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 15 October 2023, retrieved 18 October 2023 
  21. "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07. 
  22. "Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees". AMVCA - Full List: Here are all our AMVCA 9 Nominees (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-04-23. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]