Gabriel Afolayan
Appearance
Gabriel Afolayan (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1980) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí G-Fresh lágbo orin jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti akọrin ìgbàlódé. [1]. Tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni Gabriel àti Kunle Afolayan. Àgbà eléré tíátà nì Adeyemi Afolayan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀ ní bàbá wọn.
Gabriel Afolayan | |
---|---|
Afolayan at the audition for Ojuju in 2013 | |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actor, singer [2] |
Ìgbà iṣẹ́ | 1997 - present [3] |
Parent(s) | Adeyemi Afolayan (father) |
Àwọn olùbátan | Moji Afolayan (sister) Kunle Afolayan (brother) Aremu Afolayan (brother) |
Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Gold Statue
- Ojuju
- Madam Dearest
- Ija Okan
- Hoodrush
- Heroes and Zeros
- 7 Inch Curve
- Okafor's Law
- Closet (TV Series)
- Tatu
- Tomi has a gun
- Nnenna
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Tersoo, Andrella (2018-08-02). "Impressive facts from biography of Gabriel Afolayan". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-12-09.
- ↑ "Hoodrush tapped into my singing, acting talent – Afolayan". dailyindependentnig.com. Archived from the original on 27 June 2015. Retrieved 23 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Why I made a u-turn into the music industry —Afolayan". Nigerian Tribune. tribune.com.ng. Archived from the original on 10 May 2013. Retrieved 23 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)