Adeyemi Afolayan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ade Love
Ọjọ́ìbí Adeyemi Josiah Afolayan
1940
Kwara State
Aláìsí 1996
Orílẹ̀-èdè Nigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdè Nigerian
Iṣẹ́
  • actor *filmmaker *producer *director *dramatist
Years active 1976-1996
Notable work Ajani Ogun (1976)
Children Kunle Afolayan (son)
Gabriel Afolayan (Son)
Moji Afolayan (daughter)
Aremu Afolayan (son)
Relatives Toyin Afolayan (sister)

Adeyemi Afolayan (ti atun mo si Ade Love)[1] jé omo orílé èdè Nàìjíríà òsèré fiimu Yoruba, ati director.[2] O je arakunrin si oṣere Toyin Afolayan, bee na ni o je baba si awon osere bi, Kunle Afolayan, Gabriel Afolayan, Moji Afolayan ati Aremu Afolayan.[3]

Àwon fiimu tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Taxi Driver (1983)
  • Ajani Ogun (1976)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 27 February 2015. 
  2. "Dad didn’t encourage his children to act —Kunle Afolayan". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 28 February 2015. 
  3. "Saying I'm beautiful is flattery". Nigerian Tribune Newspaper. Retrieved 28 February 2015.