Aremu Afolayan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Aremu Afolayan
Ọjọ́ìbíAremu Afolayan
2 Oṣù Kẹjọ 1980 (1980-08-02) (ọmọ ọdún 43)
Ebute Metta, Ìpínlẹ̀ Èkó,
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Òsèrékùrin, Producer
Olólùfẹ́Kafilat Quadri
Parent(s)Adeyemi Afolayan (Ade Love - father)
Àwọn olùbátanMoji Afolayan (sister)
Gabriel Afolayan (brother)
Kunle Afolayan (brother)

Aremu Afolayan jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó tún jẹ́ ẹ̀gbọ́n fún òsèrékùrin Kunle Afolayan, tí ó jẹ́ òṣèré àti adarí eré tí ó gba amì-ẹ̀yẹ adarí eré tó peregedé jùlọ.[1][2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àrẹ̀mú Afọláyan jẹ́ ọmọ bíbí gbajú-gbajà adarí eré àti olùgbéré-jáde Adé Love tí ó jẹ́ ọmọ ìlú Ìgbómìnà ní Ìpínlẹ̀ Kwara.[4] Kúnlé di.ìlú-mòọ́ká látàrí eré rẹ̀ kam tí ó gbé jáde tí ó pè ní Ìdàmú Akoto ní ọdún 2009.

Ìgbé ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àrẹ̀mú fẹ́ aya rẹ̀ arábìnrin Kafilat Ọláyínká Quadri, tí wọ́n sì bímọ obìnrin kan Iyùnadé Afọláyan.

Àmì ẹyẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àmì ẹyẹ Ẹka Èsì itokasi
2021 Net Honours Most Searched Actor Wọ́n pèé [5]


Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]