Gabriel Afọláyan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Gabriel Afọláyan (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kìíní oṣù kẹta ọdún 1980) tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí G-Fresh lágbo orin jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti akọrin ìgbàlódé. [1]. Tẹ̀gbọ́n-tàbúrò ni Gabriel àti Kúnlé Afọláyan. Àgbà eléré tíátà nì Adéyẹmí Afọláyan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love nígbà ayé rẹ̀ ní bàbá wọn.

Gabriel Afolayan
Fáìlì:Gabriel Afolayan 2013.jpg
Afolayan at the audition for Ojuju in 2013
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, singer [2]
Ìgbà iṣẹ́1997 - present [3]
Parent(s)Adeyemi Afolayan (father)
Àwọn olùbátanMoji Afolayan (sister)
Kunle Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)

Àtòjọ àwọn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Tersoo, Andrella (2018-08-02). "Impressive facts from biography of Gabriel Afolayan". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-12-09. 
  2. "Hoodrush tapped into my singing, acting talent – Afolayan". dailyindependentnig.com. Archived from the original on 27 June 2015. Retrieved 23 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Why I made a u-turn into the music industry —Afolayan". Nigerian Tribune. tribune.com.ng. Archived from the original on 10 May 2013. Retrieved 23 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)