Kúnlé Afọláyan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Kunle Afolayan
Kunle Afolayan.jpg
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹ̀sán 1974 (1974-09-30) (ọmọ ọdún 46)[1]
Ebute Metta, Lagos, Lagos State, Nigeria
IbùgbéMagodo, Ikeja, Lagos State, Nigeria[2]
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Actor, Director, Producer
Olólùfẹ́Tolu Afolayan
Àwọn ọmọ4
Parent(s)Adeyemi Josiah Afolayan (Ade Love - father)
Àwọn olùbátanMoji Afolayan (sister)
Gabriel Afolayan (brother)
Aremu Afolayan (brother)

Kúnlé Afọláyan (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1974) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ọmọ bíbí Yorùbá, ní Ìgbómìnà láti ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò nígbà kan rí, ṣùgbọ́n tí ó ti di olóògbé, Adéyẹmí Josiah Afọláyan, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ade Love[3] [4]

Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kúnlé jẹ́ ọmọ bíbí Ìgbómìnà pọ́ńbélé láti ìpínlẹ̀ Kwara gẹ́gẹ́ bí a ti sọ ṣáájú. Gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò àná ni bàbá rẹ̀ Ade Love. Kúnlé kàwé gboyè nínú ìmọ̀ ìsúná ọ̀rọ̀-ajé. Ó ṣiṣẹ́ nílé ìfowópamọ́ fún ìgbà díẹ̀ kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe sinimá àgbéléwò ṣíṣe lọ́dún 2015. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti ń kópa ní ìwọ̀nba kí ó tó di àkókò yìí. Kúnlé máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa tó ṣòódó. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ sìn ni àmìn ẹ̀yẹ tí ó gbà gẹ́gẹ́ bí eléré tíátà.[5] [6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Its Kunle Afolayan’s birthday". The Nation. Archived from the original on 2014-10-07. Retrieved 24 October 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Kunle Afolayan Shows Off His New House In Magodo". Star Gist. Archived from the original on 2016-09-19. Retrieved 16 September 2016.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Kunle Afolayan Biography, History, Asset and Net Worth - Austine Media". Austine Media. 2018-05-20. Retrieved 2019-12-09. 
  4. "Kunle Afolayan". Leadership Newspaper. 2019-04-07. Retrieved 2019-12-09. 
  5. Hoad, Phil (2012-10-30). "Out of Africa: Kunle Afolayan bids to bring Nollywood cinema to the world". the Guardian. Retrieved 2019-12-09. 
  6. "BIOGRAPHY". OKIKI AFOLAYAN CONCEPTS. 2018-01-31. Retrieved 2019-12-09.