Irapada
Ìrísí
Ìràpadà | |
---|---|
Adarí | Kunle Afolayan |
Àwọn òṣèré | Kunle Afolayan |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Owó àrígbàwọlé | ₦5,000,000 (domestic gross)[1] |
Irapada (English: Redemption) jẹ́ eré adẹ́rùbani tí wọ́n gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2006, tí Kunle Afolayan sì jẹ́ olùdarí eré náà. [2] Ní ọdún 2017, eré náà gba amì-ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award for Best Film in an African Language. Fiimu náà tún wà lara àwọn eré tí wọ́n gba amì-ẹ̀yẹ Best African Films of the 21st century CNN ní African Voices in 2013'. [3][4][5] It was released on DVD in July 2008.[6][7][8]
Àwọn Itọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Leu, Bic (14 January 2011). "Nollywood goes for new models to curb piracy". The Guardian Newspaper. Finding Nollywood. Archived from the original on 2 April 2015. Retrieved 11 March 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ ""Irapada has not been fairly judged”.......Kunle Afolayan". modernghana.com. Retrieved 11 September 2014.
- ↑ "Must-see African movies of the 21st century". CNN edition.cnn.com. Retrieved 22 October 2014.
- ↑ "Leila Djansi’s Sinking Sands Listed On CNN Among 10 Must-See African Films". news1ghana.com. Retrieved 22 October 2014.
- ↑ "White Waters” & “Irapada” Make CNN’s Must See African Movies Of The 21st Century List - See the Full List". Archived from the original on 22 October 2014. Retrieved 11 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "IRAPADA MOVIE GOES ON SALE IN JULY". thenigerianvoice.com. Retrieved 11 September 2014.
- ↑ "Watch Kunle Afolayan’s ‘Irapada’ & ‘The Figurine’ free". gistus.com. Retrieved 11 September 2014.
- ↑ "Redemption". theguardian.com. https://www.theguardian.com/film/movie/120947/redemption. Retrieved 11 September 2014.
Àdàkọ:Africa Movie Academy Award for Best Film in an African Language Àdàkọ:Kunle Afolayan