The Bridge (2017 film)
Ìrísí
The Bridge | |
---|---|
Adarí | Kunle Afolayan |
Olùgbékalẹ̀ | Lasun Ray Eyiwumi |
Òǹkọ̀wé | Shola Dada |
Àwọn òṣèré | Chidinma Ekile Demoal Adedoyin Tina Mba Ayo Mogaji Zack Orji Bayo Salami |
Orin | Anu Afolayan Kent Edunjobi |
Olóòtú | Adelaja Adebayo |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Lasun Ray Films |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 118 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
The Bridge jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2017, èyí tí Kunle Afolayan darí, tí ó sì ṣàtẹ̀jádé.[1][2]
Àhunpọ̀ ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọmọọba kan láti ìdílé ọlọ́ba pinnu láti fẹ́ ọmọbìnrin kan tó wá láti ìdílé ọlọ́lá, àmọ́ àwọn òbí ọmọbìnrin náà ò fọwọ́ si nítorí wọn ò kì í ṣe ẹ̀yà kan náà. Èyí sì mú kí àwọn méjèèjì lọ́ fẹ́ ara wọn lẹ́yìn àwọn òbí wọn. Èyí sì mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan máa dàrú fún wọn.[3][4][5]
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Chidinma bí i Stella Maxwell
- Demola Adedoyin bí i Obadore Adeyemi
- Kunle Afolayan bí i Jire
- Zack Orji bí i Dominic Maxwell
- Tina Mba bí i Mrs. Maxwell
- Prof. Ayo Akinwale bí i Obe Adeyemi
- Binta Ayo Mogaji bí i Olori Omolade
- Ken Erics bí i Augustine
- Peter Johnson bí i Pascal
- Akinruli Akinola bí i Arinze
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "The Bridge | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 October 2020. Retrieved 3 November 2019.
- ↑ nollywoodreinvented (13 September 2019). "The Bridge". Nollywood REinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 November 2019.
- ↑ "5 things you should know about Kunle Afolayan's new movie". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 November 2017. Retrieved 3 November 2019.
- ↑ "Review- The Bridge (2017)". diaryofamovielover.blogspot.com. Retrieved 3 November 2019.
- ↑ "MM Review: 'The Bridge' Directed by Kunle Afolayan". MamaZeus (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 December 2017. Archived from the original on 5 March 2020. Retrieved 3 November 2019.