Jump to content

Ken Erics

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ken Erics
Ọjọ́ìbíEkenedilichukwu Ugochukwu Eric Nwenweh
28 Oṣù Kejì 1985 (1985-02-28) (ọmọ ọdún 39)
Kano, Kano State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaNnamdi Azikiwe University, Awka
Iṣẹ́Actor, writer, producer, musician, politician
Ìgbà iṣẹ́2001–present
Websitehttps://kenericsofficial.com/

Ekenedilichukwu Ugochukwu Eric Nwenweh, tí àlàjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Ken Erics Ugo tàbí Ken Erics jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti ọ̀kọrin, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré sinimá kan tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ The Illiterate eré tí òṣèrébìnrin Tonto Dikeh àti Yul Edochie ti kópa.[1]Ó sì tún jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anabra.

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Eọ́n bí Eric ní Ìpínlẹ̀ Kano, ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejì ọdún 1985.[2]. Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀tà Igbo ní apá ìlà Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Binta Mustapha ScienceÌpínlẹ̀ Kano. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Dennis Memorial Grammar (DMGS) ní ìlú Onitsha, ní Ìpínlẹ̀ Anambra Erics ti nífẹ́ sí eré ṣiṣẹ́ láti ìgbà tí ó ti wà ní kékeré.[3] Ó lọ zí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Nnamdi Azikiwe ní ìlú Awka*Ìpínlẹ̀ Anambra tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ eré-oníṣe.[4] Ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè kejì nínú ìmọ̀ eré oníṣẹ́ àti sinimá bákan náà.

Eric bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé ní inú ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré ‘Holy Prostitute’ eré tí Chris Ubani darí rẹ̀.[5] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa wẹ́wẹ̀wẹ́ ní irí àwọn eré sinimá àgbéléeò ọlọ́kan-ò-jọkan, láìpẹ́, ipa rẹ̀ tí ó kó nínú tí àkọ́lénrẹ̀ ń jẹ́ Ugo, eré yí ni ó s9ọ́ di ààyò àwọn ènìyàn nínú àwọn eré rẹ̀ tí ó kù. [6]Èyí ni ó sì tún ṣí àwọn ọ̀nà ànfaní mìíràn fun nínú agbo Nollywood. As a writer, Erics first published work "Cell 2"[7]Ó ti di ìlú-mòọ́ká, wọ́n sì ti m lòó nínú àwọn eré orísiríṣi ati awọn àpilẹ̀kọ eré oníṣẹ́ gbogbo ní orí-ìtàgé àwọn àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo. Eric ma ń kọrin ní ìgbà míràn tí ó sì ma ń ta jìtá ati keyboard nínú orin rẹ̀.[8] Ó ti kọ àwọn orin ọlọ́kan-ò-jọkan fún àwọn sinimá àgbéléwò pẹ̀lú. Òun àti àwọn òṣèré jànkàn-jànkàn bíi: Ngozi Ezeonu, Yul Educhie, Desmond Eliot, Chinwetalu Agu, Regina Daniels àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ọdún 2014, Eric gba amì-ẹ̀yẹ fún Òṣèré kúnrin amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ amì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Award[9]Ó tún gba amì-ẹ̀yẹ fún Òṣèré kùrin aléwájú tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti Afrifimo Awards ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ní ọdún 2015, ó gba amì-ẹ̀yẹ ti Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti City People Entertainment Award.[10]

Ní ọdún 2017, Erics tún gba amì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards 2017 fún Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ Ó sì gba amì-ẹ̀yẹ fún ti Golden Movie Awards ní ọdún 2018 gẹ́gẹ́ bí Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ.

Àwọn Amì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Ayẹyẹ Amì-ẹ̀yẹ Ẹni tí ó gbàá Èsì
2014 City People Entertainment Awards Best Supporting Actor Ken Erics Gbàá
2014 Afrifimo Awards (USA) Best Lead Actor Ken Erics Gbàá
2015 Golden Icons Movie Awards (GIAMA) 2015 Awards Best Actor in a Lead Role Ken Erics Wọ́n pèé
Golden Icons Movie Awards (GIAMA) 2015 Awards Best 'on-screen duo' Ken Erics and Kiki Omeili Wọ́n pèé
City People Entertainment Awards Best Actor Ken Erics Gbàá
Afrifimo Awards (USA) Best 'on-screen duo' Ken Erics Wọ́n pèé
2017 City People Entertainment Awards Best Actor Ken Erics Gbàá
Nollywood Ambassadors Awards Best Actor of the Year Ken Erics Gbàá
2018 Golden Movie Awards (GMA) 2018 Best Supporting Actor Ken Erics Wọ́n pèé
2019 South South Achievers Awards (SSA) 2019 Male Actor of the Year Ken Erics Gbàá

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Movie Roles

Year Title Role Director Notes
2002 Holy Prostitute Doctor Chris Ubani Cameo Role
2006 Silence of the gods Onyegbula Teco Benson Home Video
2007 Eran and Erak Oliver Theodore Anyanji Feature Film
2010 Evil intention Santos Ugezu j Ugezu Feature Film
2011 Gold not Silver Nwokolo Tchidi Chikere Feature Film
2011 A Better Tomorrow Izu Michael JaJa Feature Film
2011 Days of Gloom Izu Michael JaJa Feature Film featuring John Dumelo, Olu Jacobs and Chioma Chukwuka
2012 The Illiterate Ugo Silvester Madu Feature Film
2013 Release me oh Lord Osita Ifeanyi Ogbonna Feature Film
2014 Father Muonso Father Elijah Vincent De Anointed Feature Film
2014 Burning Bridges Louis Okechukwu Oku Feature Film
2014 Sugarcane Azuka Obinna Ukeze Feature Film
2015 Trials of Igho Igho Chris Eneaji Lead/Feature Film
2015 Echoes of Love Prince Ugezu j Ugezu Feature Film
2015 Omalicham Jeremiah Ugezu j Ugezu Feature Film
2016 Almost Perfect Nonso Desmond Elliot Feature Film
2016 Within these walls Francis Uche Jombo Feature Film
2016 Valerie Joe Taiwo Shittu Feature Film
2016 The Vengeance Jeff Goodnews Erico Isika Feature Film
2016 Okafor's Law Chuks A.k.A Fox Omoni Oboli Feature Film featuring Blossom a Chukwujekwu, Richard Mofe Damijo , Omoni Oboli
2017 Crossed Path Jesse Frank Rajah Arase Feature Film featuring Okawa Shaznay, Frank Artus & Emem Inwang
2017 What Lies Within[11] Brian Vanessa Nzediegwu Feature Film with Michelle Dede, Tope Tedela, Kiki Omeili
2017 Omugwo Raymond Kunle Afolayan Feature Film featuring Patience Ozokwo, Ayo Adesanya, Omowunmi Dada
2017 Body Language Lancelot Moses Inwang Feature Film featuring Ramsey Nouah, Tana Adelana
2017 The Bridge Augustine Kunle Afolayan Feature Film featuring Chidinma Ekile, Demola, Adedoyin, Zach Orji
2017 Fate Of Amanda
2018 You Are My Light Samson Vincent D Anointed Feature Film produced by Ken Erics and featuring Yvonne Jegede, Ebele Okaro
2019 Love Melody Obiora Ability Tagbo Feature Film produced by Ken Erics and featuring Rachael Okonkwo
2019 Ordinary Fellows[12] Ekene Lorenzo Menakaya and Ikenna Aniekwe Feature Film featuring Wale Ojo, Chiwetalu Agu and Somadina Adinma

Ipa rẹ̀ lórí eré orí amóhù-máwòrán

Year Title Role Director Notes
2005 Webs Livinus Otteh TV Series
2015 Growing Old Chidi Chris Eneaji TV Series

Stage Plays

Title Role Writer
Hopes of the Living Dead Hacourt Whyte Ola Rotimi
Trials of Oba Ovoramnwen Consular Ola Rotimi
Hangmen Also Die R.I.P Esiaba Irobi
Childe International Chief Wole Soyinka
Everyman Everyman Obotunde Ijimere
Grip Am Ise Ola Rotimi
Gold, Frankincense and Myrrh Prof Ogun Esiaba Irobi


  • Inozikwa Omee (2018)
  • Thank You Baba (2019)
  • Mama (2019)
  • Many Mysteries (2019)
  • Sugarcane Baby (2019)
  • Pretence (2019)
  • Anom Gi N’aka (2019)
  • Love is Life (2019)

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Favour, Ugochukwu (18 January 2013). "TONTOH DIKE, KEN ERICS, EDOCHIE STARS, THE ILLITERATE". Nigeria Films (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 31 March 2016. https://web.archive.org/web/20160331141727/http://www.nigeriafilms.com/news/19723/16/tontoh-dike-ken-erics-edochie-stars-the-illiterate.html. Retrieved 7 June 2016. 
  2. Ola, Erinfolami (28 February 2014). "Nollywood Celebrities Birthday". Naijagists (Lagos, Nigeria). http://naijagists.com/nollywood-celebrities-birthday-ken-erics-teco-benson-lilian-bach-a-year-older-today/. Retrieved 7 June 2016. 
  3. Emedolibe, Ngozi (9 March 2016). "My childhood interesting, entertaining —Ken Erics". National Mirror Newspaper (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 14 March 2016. https://web.archive.org/web/20160314143834/http://nationalmirroronline.net/new/my-childhood-interesting-entertaining-ken-erics/. Retrieved 7 June 2016. 
  4. Bassey, Wisdom (12 January 2015). "Interview with Actor Ken Erics One of Nollywood's Emerging faces". Daily Mail Nigeria (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 6 May 2017. https://web.archive.org/web/20170506081139/http://dailymail.com.ng/interview-with-ken-erics-one-of-nollywoods-emerging-faces/. Retrieved 7 June 2016. 
  5. Izuzu, Chidumga (29 February 2016). "Ken Erics: 5 things you probably don't know about actor". The Pulse Ng. Lagos, Nigeria. Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 17 November 2020. 
  6. Sean, Sean (24 November 2014). "Interview With Nollywood Ken Eric, One Of Nigeria's Movie Industry Emerging Faces". Daily Mail Nigeria. Lagos, Nigeria. Archived from the original on 2 February 2017. Retrieved 17 November 2020. 
  7. Izuzu, Chidumga (29 February 2016). "Cell 2". Amymuses's Blog. Lagos, Nigeria. 
  8. Izuronye, Ernesta (28 February 2016). "Nollywood Actor Ken Erics Has A Passion for Music (Photos)". Nollywood Community. Lagos, Nigeria. 
  9. Lere, Success (23 June 2014). "List Of Winners at City People Entertainment Awards 2014". Gistmainia. Lagos, Nigeria. 
  10. Lere, Mohammed (18 August 2015). "Nollywood: List of celebrities who win at the 2015 city People Award". Premium Times. Lagos, Nigeria. 
  11. https://dailytimes.ng/entertainment/tope-tedela-produces-first-movie/
  12. "Wale Ojo, Somadina Adinma and Chiwetalu Agu star in “Ordinary Fellows,” new Nollywood movie produced by Lorenzo Menakaya » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-07. Retrieved 2020-05-17. 

Àdàkọ:Authority control