Uche Jombo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Uche Jombo
Ọjọ́ìbíUche Jombo
December 28, 1979 (1979-12-28) (ọmọ ọdún 44)
Enugu
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Ẹ̀kọ́University of Calabar
Iṣẹ́Actress, Film Producer, director, Writer
Olólùfẹ́Kenney Rodriguez
Àwọn ọmọMatthew Rodriguez

Uche Jombo Rodriguez tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1979 (December 28, 1979), jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti oǹkọ̀tàn àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ Nàìjíríà.

Ìgbésí ayé rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Uche Jombo sí ìlú Abiriba, ní Ìpínlẹ̀ Abia, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1979. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì nínú ìmọ̀ ìṣirò àti àtò-iye (Mathematics and Statistics) ní yunifásítì, University of Calabar, àti ìmọ̀ nípa Ètò Ìmọ̀ Ẹ̀rọ Kọ̀m̀pútà Computer ProgrammingFederal University of Technology Minna.[1][2]

Àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Sinimá Ẹ̀dá-ìtàn Àkíyèsí
1999 Visa to hell[3]
2000 Girls Hostel with Mary Uranta[4]
2002 Fire Love pẹ̀lú Desmond Elliot
2004 Scout pẹ̀lú Alex Lopez
2005 Endless Lies Becky pẹ̀lú Desmond Elliot
Darkest Night pẹ̀lú Genevieve Nnaji, Richard Mofe Damijo àti Desmond Elliot
Black Bra
2006 Secret Fantasy pẹ̀lú Ini Edo
Price of Fame pẹ̀lú Mike Ezuruonye àti Ini Edo
My Sister My Love Hope pẹ̀lú Desmond Elliot
Love Wins Ege pẹ̀lú Desmond Elliot
Co-operate Runs pẹ̀lú Zack Orji
2007 World of Commotion pẹ̀lú Zack Orji àti Mike Ezuruonye
Rush Hour
Price of Peace pẹ̀lú Chioma Chukwuka àti Jim Iyke
Most Wanted Bachelor pẹ̀lú Ini Edo àti Mike Ezuruonye
Keep My Will pẹ̀lú Genevieve Nnaji àti Mike Ezuruonye
House of Doom pẹ̀lú Zack Orji àti Mike Ezuruonye
Greatest Harvest pẹ̀lú Pete Edochie
Final Hour pẹ̀lú Tonto Dikeh
2008 Feel My Pain pẹ̀lú Mike Ezuruonye
Beyonce & Rihanna Nichole pẹ̀lú Omotola Jalade-Ekeinde, Nadia Buari àti Jim Iyke
2009 Love Games pẹ̀lú Jackie Appiah àti Ini Edo
Entanglement pẹ̀lú Desmond Elliot, Mercy Johnson àti Omoni Oboli
Silent Scandals Muky with Genevieve Nnaji & Majid Michel[5]
2010 Home in Exile pẹ̀lú Desmond Elliot
Holding Hope Hope pẹ̀lú Desmond Elliot àti Nadia Buari
2011 Kiss and Tell Mimi pẹ̀lú Desmond Elliot àti Nse Ikpe-Etim
Damage[6] pẹ̀lú Tonto Dikeh
2012 Mrs Somebody Desperado
2012 Misplaced Debra with Van Vicker
2013 After The Proposal Mary with Patience Ozokwor and Anthony Monjaro
2016 Wives on strike[7] pẹ̀lú Chioma Chukwuka and Omoni Oboli
2017 Banana Island Ghost[8] pẹ̀lú Chigul àti Dorcas Shola Fapson
2018 Heaven On My Mind[9] Uju with Ini Edo

2016 Lost in Us pẹ̀lú Okey Uzoeshi

2018 How I Saved My Marriage

Àwọn ìgbóríyìn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Ètò Àmìn-ẹ̀yẹ Àkọ́lé sinimá Èsì
2008 AfroHollywood Awards -UK Òṣèrébìnrin tó dára jù GbàáÀdàkọ:Cn
4th Africa Movie Academy Awards Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tó dára jù Keep My Will Yàán
2010 2010 Best of Nollywood Awards Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèrébìnrin tó dára jù Silent Scandals Gbàá
City People Entertainment Awards Òṣèrébìnrin tó dára jù GbàáÀdàkọ:Cn
Abia State Awards Àmìn ìbọláfún Herself Gbàá
Life Changers Awards-UK Gbajúmọ̀ òṣèré Nollywood lọ́dún naa Herself Gbàá
5 Continents Awards -New York Àmìn-ẹ̀yẹ afowóṣàánú Herself GbàáÀdàkọ:Cn
2011 ELOY awards Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Damage GbàáÀdàkọ:Cn
2011 Best of Nollywood Awards Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Damage Yàán
Òṣèré ojú ìran tó dára jù Yàán
Olùfẹnukẹnu to dára jù pẹ̀lú Kalu Ikeagwu Yàán
2012 Nafca Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Damage Gbàá
Best Film Gbàá[10]
2012 Golden Icons Academy Movie Awards Àmìn-ẹ̀yẹ ààyò àwọn òlùwòran tó dára jù herself Yàán
8th Africa Movie Academy Awards Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Damage Yàán
2013 Africa International Film Festival Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Lies Men Tell Gbàá[11]
2013 Best of Nollywood Awards Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù sinimá èdè Gẹ̀ẹ́sì Mrs Somebody Yàán
2014 ELOY Awards[12] Olóòtú obìnrin tó dára jù lọ́dún N/A Wọ́n pèé
2014 Golden Icons Academy Movie Awards Akópà ìran tó dára jù pẹ̀lú (Patience Ozokwor) After The Proposal Yàán
Àmìn-ẹ̀yẹ àwọn òlùwòran tó dára jù Herself Yàán
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards Sinimá aláwàdà to dára jù Lies Man Tell Yàán
10th Africa Movie Academy Awards Olú-ẹ̀dá-ìtàn òṣèrébìnrin tó dára jù Lagos Cougars Yàán
2015 2015 Golden Icons Academy Movie Awards Òṣèrébìnrin tó dára jù oge's sister Yàán
Female Viewers Choice Herself Gbàá

Àwọn ìtọ́kasí ìta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Authority control [https://www.latestnigeriannews.com/news/6488060/heaven-on-my-mind-isnt-a-christian-film-uche-jombo.html [http://guardian.ng/saturday-magazine/uche-jombos-heaven-on-my-mind-is-still-trending/ [https://www.vanguardngr.com/2018/10/uche-jombo-ini-edo-collaborate-on-new-movie-heaven-on-my-mind/[https://leadership.ng/2018/10/12/uche-jombo-debuts-heaven-on-my-mind/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] [http://thenationonlineng.net/ini-edo-why-i-agreed-to-work-with-uche-jombo/ [https://www.pulse.ng/entertainment/movies/uche-jombo-releases-trailer-for-new-https://naijagists.com/heaven-on-my-mind-nigerian-movie-release-date-uche-jombo/movie-heaven-on-my-mind-id8995753.html)https://guardian.ng/saturday-magazine/uche-jombos-heaven-on-my-mind-is-ready/ [http://xplorenollywood.com/nta-uche-jombo-releases-poster-for-heaven-on-my-mind-a-directorial-debut/ [https://ynaija.com/heres-when-uche-jombos-directorial-debut-heaven-on-my-mind-will-hit-cinemas/ [https://www.stelladimokokorkus.com/2018/10/actors-uche-jombo-and-ini-edo-set-for.html

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Glo Ambassadors - Uche Jombo". Lagos, Nigeria: Globacom Limited. Archived from the original on 26 September 2011. Retrieved 28 September 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Adeniran, Yemisi (10 September 2011). "I found acting boring -Uche Jombo". National Mirror (Lagos, Nigeria: Global Media Mirror Limited). Archived from the original on 8 June 2012. https://web.archive.org/web/20120608185706/http://nationalmirroronline.net/entertainment/celebrity/20296.html. Retrieved 28 September 2011. 
  3. Olatunji, Samuel (26 June 2011). "Nollywood’s ‘A’ list stars". Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/june/26/showtime-26-06-2011-001.html. Retrieved 28 September 2011. 
  4. Erhariefe, Tony (2013-04-28). "Mary Uranta: Sexual harassment drove me out of Nollywood". Sunnewsonline.com (Daily Sun). Archived from the original on 2014-04-19. https://web.archive.org/web/20140419015616/http://sunnewsonline.com/new/?p=24700. Retrieved 2014-04-18. 
  5. "Silent Scandals hits movie shelves soon". Vintage Press Limited. Archived from the original on 26 July 2011. Retrieved 28 September 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Uche Jombo Storms Cinemas With Damage". AllAfrica.com. 28 July 2011. http://allafrica.com/stories/201108010242.html. Retrieved 28 September 2011. 
  7. "Watch the Trailer for "Wives On Strike" starring Uche Jombo, Omoni Oboli, Ufuoma McDermott & More". BellaNaija. Retrieved 2016-05-12. 
  8. "Banana Island Ghost Full Cast". Uzomedia. Retrieved 2017-05-20. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  9. "Uche Jombo’s heaven on my mind is still trending". Guardian NG. Retrieved 2019-04-21. 
  10. "Uche Jombo wins Best Actress at NAFCA - Vanguard News". 21 September 2012. 
  11. "Desmond Elliot, Uche Jombo win big at AFRIFF - The Nation Nigeria". 18 November 2013. 
  12. "Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Retrieved 20 October 2014.