Banana Island Ghost

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Banana Island Ghost (Òkú Erékùsù Ọ̀gẹ̀dẹ̀) jẹ fiimu ti a gbe jáde ni ọdún 2017. Olùkọ̀tàn àti oludari fiimu naa ni BB Sasore Olùdarí Àgbà fiimu naa ni Derin Adeyọkunnu ati Biọla Alabi. Àwon òṣèré tí o kó'pa ninu fiimu naa ni Ali Nuhu, Saheed Balogun, Tina Mba àti Bimbo Manuel.[1]

Àwon tí o kó'pa nínú rẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Saheed Balogun
  • Ali Nuhu
  • Tina Mba
  • Uche Jombo
  • Bimbo Manuel
  • Dorcas Shola Fapson

Àgbéka'lẹ̀ eré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìtẹ́wọ́gbà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àjọ tí o ńṣe àgbéyẹ̀wò fiimu ti a n pe ni Nollywood Reinvented fún fiimu yi ni àmì ìdá mọ́kàn-dín-lọ́gọ́ta nínú ọgọrun (59% rating). [2]

Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help)