Jump to content

Saheed Balogun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saheed Balógun
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kejì 1967 (1967-02-05) (ọmọ ọdún 57)
Kwara State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaKwara State Polytechnic
Iṣẹ́
  • Òṣèré
  • Oníṣẹ́ Sinimá
  • Olùgbéré jáde
  • Adarí fíìmù
  • Ìgbà iṣẹ́1978–presentNotable workÒfin mósèOlólùfẹ́
    Saheed Balógun ni wọ̣́n bí ní ọjọ́ Karùún oṣu Kejì ọdún 1967 (February 5, 1967)  ní ìpínlẹ̀ Kwara. Ó jẹ́ gbajú-gbajà òṣèré orí-ìtàgé, olùgbéré jáde, adarí eré, àti olùṣe fíímù ilẹ̀ Nàìjíríà.

    [1][2]

    Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ rẹ̀

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

     Wọ́n bí Saheed ní ìpínlẹ̀ Kwara tí ó jẹ́ (North Central Nigeria), ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Níbi tí ó ti kàwé alákọ̀ọ́ bẹ̀rẹ̀ , ìwé girama àti ilé ìwé gíga .[3] Ó kàwé jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ 'Kwara State Polytechnic' tí wọ́n ti yí padà sí (Kwara State University).[4] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 1978, nígbà tí ó kọ́kọ́ ṣe ètò rẹ̀ kan lórí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán tí ó pè ní "Youth Today" lórí NTA.[5] Ó ṣe sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ 'City Girl' ní ọdún 1989, àmọ́ tí ó sì ti gbé ọ̀pọ̀ sinimá jáde tí ó sì tún ti ṣe adarí fún ọ̀pọ̀ eré orí-ìtàgé mìíràn rẹpẹtẹ.[6]

    Àwọn ẹbí rẹ̀

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

    Ó fẹ́ ìyàwó rẹ̀ tí òun náà jẹ́ òṣèré orí ìtàgé ìyẹn Fathia Balogun ṣùgbọ́n wọ́n ti pínyà báyìí. Ó bí ọmọ ọkùnrin kan Khalid Balógun àti obìnrin kan Aliyah Balógun.[7]

    Lára àwọn sinimá tó ti ṣe ni:

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    • Modúpẹ́ Tèmi ( Thankful ) - The first two cast movie in Africa
    • Gbogbo Èrè ( Total profit ) - The first three cast movie in west Africa
    • Third Party - The first ever ankara movíe in Africa
    • Òfin mósè (2006).
    • Family on Fire (2011)

    Àwọn ìtọ́ka sí

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    1. https://web.archive.org/web/20150218103942/http://www.punchng.com/entertainment/e-punch/yoruba-actors-not-under-any-spell-saheed-balogun/. Archived from the original on February 18, 2015. Retrieved February 16, 2015.  Missing or empty |title= (help)
    2. https://web.archive.org/web/20150218103936/http://www.punchng.com/entertainment/saturday-beats/people-should-learn-from-my-past-marriage-saidi/. Archived from the original on February 18, 2015. Retrieved February 16, 2015.  Missing or empty |title= (help)
    3. https://web.archive.org/web/20150216215221/http://www.thisdaylive.com/articles/saheed-balogun-talks-about-my-failed-marriage-distract-my-creativity/176553/. Archived from the original on February 16, 2015. Retrieved February 16, 2015.  Missing or empty |title= (help)
    4. "Saheed Balogun: Talks About My Failed Marriage Distract My Creativity". Thisday. April 14, 2014. Archived from the original on February 16, 2015. Retrieved January 19, 2014. 
    5. Empty citation (help) 
    6. Empty citation (help) 
    7. Empty citation (help)