Chioma Chukwuka
Ìrísí
Chioma Chukwuka - Akpotha | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹta 1980 Lagos State |
Orílẹ̀-èdè | Naijiria |
Iṣẹ́ | Actress, Film Maker |
Olólùfẹ́ | Franklyn Akpotha( m.2006–present) |
A bi Chioma Chukwuka ni ọjọ́ kejila Oṣu Kẹta ọdun 1980. A tun n pe orúkọ rẹ̀ ni Chioma Chukwuka Akpotha tabi Chioma Akpotha, o jẹ́ oṣere ati olugbekale fiimu ni orile-ede Naijiria. Ni ọdun 2007 o gba Ami Ẹyẹ ti àwọn osere tiata fún ilẹ Afrika gẹgẹbi obinrin ti o dara julo ti o si kopa gegebi osere akoko lobinrin ninu ere ati ami eye fun awon alawodudu ni Hollywood gegebi oṣere lobinrin ti o dara ju lọ. [1][2] [3]