Van Vicker

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Joseph van Vicker
Van Vicker in 2016
Ọjọ́ìbíJoseph van Vicker
1 Oṣù Kẹjọ 1977 (1977-08-01) (ọmọ ọdún 46)
Accra, Ghana
Iléẹ̀kọ́ gígaAfrican University College of Communications
Iṣẹ́Film and television actor
Ìgbà iṣẹ́2000–present
Awards
  • 2009 Afro-Hollywood Award
  • 2011 Pan African Film Festival
  • 2012 Nafca
  • 2013 Ghana movie awards
  • Pyprus Magazine Screen Actors Awards
  • KumaWood Awards 2016
Websitevanvicker.org

Joseph van Vicker (tí wọ́n bí ní 1 August 1977),[1] tí wọ́n tún mọ̀ sí Van Vicker, jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana, ó sì tún jẹ́ olùdarí eré àti aṣèfẹ́-ọmọnìyàn. Òun ni olùdarí ilé-iṣẹ́ Sky + Orange production, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe fíìmù. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ méjì, àkọ́kọ́ fún "Òṣèrékùnrin tó dára jù nínú eré" àti "Òṣèrékùnrin tó ń di gbajúmọ̀ bọ̀" ní Africa Movie Academy Awards, ní ọdún 2008.[2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Vicker ní ìlú Accra, ní Ghana. Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ghana tó tan mọ́ ilẹ̀ Liberia[4], bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ará Netherland.[5][6][7] Bàbá rẹ̀ kú nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́fà.[6]

Vicker lọ sí ilé-ìwé Mfantsipim,[8] pẹ̀lú òṣèrékùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Majid Michel. Ó gboyè ẹ̀kọ́ ní African University College of Communications, ní ọdún 2021.[9]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Olùgbà Èsì
2008 4th Africa Movie Academy Awards Best Actor in a Leading Role The Return of Beyonce/Princess Tyra Wọ́n pèé
Best Upcoming Actor Wọ́n pèé[2][3]
2009 Afro-Hollywood Award Best Actor (African film category) Gbàá[10][11]
2010 2010 Ghana Movie Awards Best Actor Leading Role (Local Film) Dna Test Yàán
2011 2011 Ghana Movie Awards Best Actor Leading Role Paparazzi Yàán
2011 Pan African Film Festival Africa Channel's Creative Achievement Award Himself Gbàá[12]
2012 Nafca Best Comedy Movie Joni Waka Gbàá
2013 2013 Ghana Movie Awards Best Actor (Local Film) Joni Waka Gbàá[13]
Pyprus Magazine Screen Actors Awards Best International Actor Gbàá
2014 2014 Ghana Movie Awards Favourite Actor Yàán
2015 Nafca Best Actor in a Leading role (Diaspora film) Heart Breaker's Revenge Wọ́n pèé
2016 2016 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Actor Drama/Series A long Night Yàán
2016 Nigeria Entertainment Awards Best Actor Africa/Non Nigerian Yàán
KumaWood Awards Best Collaboration Broni W'awu Gbàá

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún Fíìmù Ojúṣe Ọ̀rọ̀
2004 Divine Love with Majid Michel & Jackie Appiah
2006 Beyonce: The President's Daughter Raj with Nadia Buari & Jackie Appiah
Darkness of Sorrow CK (Charles) with Nadia Buari
Mummy's Daughter with Nadia Buari & Jackie Appiah & Okediji Alexandra
The Return of Beyonce Raj with Nadia Buari & Jackie Appiah
2007 American Boy "Nelly" with Nadia Buari
I Hate Women Rocky with Jackie Appiah
Innocent Soul
In the Eyes of My Husband Leo with Nadia Buari
Princess Tyra Kay with Jackie Appiah, Yvonne Nelson
Royal Battle Lawrence with Majid Michel & Jackie Appiah
Slave to Lust with Nadia Buari, Ini Edo, Mike Ezuruonye & Olu Jacobs
Wedlock of the Gods
2008 Broken Tears Ben with Genevieve Nnaji & Kate Henshaw
Corporate Maid Desmond
Friday Night
Jealous Princess Sam with Chika Ike & Oge Okoye
River of Tears Ben with Genevieve Nnaji & Kate Henshaw
Total Love Nick[citation needed] with Jackie Appiah
2009 Twilight Sisters Micky with Oge Okoye
Royal War Uzodimma with Ini Edo, Rachael Okonkwo
2009 Beyond Conspiracy[14] Michael
2010 Discovered[14]
2010 Loyal Enemies[14]
2010 Kingdom in Flames[15]
2011 Paparazzi: Eye in the Dark Rich
2013 One Night In Vegas Tony with Jimmy Jean-Louis, Michael Blackson, Sarodj Bertin
2014 The Heart Breaker's Revenge Dalyboy with Dalyboy Belgason, Brittany Mayti, Sarodj Bertin
2016 Skinned Robert/ Bobby with LisaRaye McCoy, Jasmine Burke
2017 Cop's Enemy Christopher "Shadow" Ifechi
Pending Day After Death with Wema Sepetu

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "birthday". Theafricandream.net. 25 July 2020. Retrieved 25 July 2020. 
  2. 2.0 2.1 "Africa Movie Academy Awards' nominees take a bow in Josies". Archived from the original on 8 February 2010. Retrieved 23 October 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. 3.0 3.1 "AMAA Nominees and Winners 2008". Africa Movie Academy Award. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 7 March 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Nigeria: Growing Up Without a Father Made Me Tough- Van Vicker". Allafrica.com. Retrieved 28 November 2021. 
  5. Olatunji, Samuel (21 January 2010). "My life, my story, my wife— Van Vicker". The Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showpiece/2010/jan/31/showpiece-31-01-2010-001.htm. 
  6. 6.0 6.1 "Van's Biography". Vanvicker.com. Archived from the original on 28 March 2009. Retrieved 7 March 2011. 
  7. "Van Vicker (the well-known African actor) in Boston". Belmizikfm.com. Massachusetts, USA. 6 May 2009. Archived from the original on 27 February 2012. Retrieved 7 March 2011. 
  8. "Van Vicker". .ghanacelebrities.com. Retrieved 22 February 2015. 
  9. "Van Vicker finally graduates from university after 24 years". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-26. Retrieved 2021-07-27. 
  10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named source1
  11. Akande, Victor (15 November 2010). "London agog for Afro Hollywood Award 2009". The Nation (Lagos, Nigeria). http://thenationonlineng.net/web2/articles/25360/1/London-agog-for-Afro-Hollywood-Award-2009/Page1.html. 
  12. "Van Vicker To Receive Creative Award At The 20th Annual Pan African Film Festival", News Ghana, 1 February 2012.
  13. "Nadia Buari & Van Vicker Bag Best Actress and Actor at 2012 Ghana Movie Awards". twimovies. Archived from the original on 15 November 2021. Retrieved 30 August 2015. 
  14. 14.0 14.1 14.2 "Van Vicker". Van Vicker (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 10 August 2016. Retrieved 23 April 2016. 
  15. "Movies". Van Vicker (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 10 August 2016. Retrieved 23 April 2016.