Kate Henshaw

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Kate Henshaw
Kate Henshaw at Lawrence Onochie 50th birthday09 04 40 659000.jpeg
Kate Henshaw at Pastor Lawrence Onochie 50th birthday celebration in Ikeja, Lagos State, Nigeria, 2019
Ọjọ́ìbíKate Henshaw
19 Oṣù Keje 1971 (1971-07-19) (ọmọ ọdún 49)
Calabar, Cross River, Nigeria
Iṣẹ́Actress
Àwọn ọmọGabrielle Nuttall
Àwọn olùbátanAndre Blaze (cousin)

Kate Henshaw tí wọ́n tún máa ń pè ní Kate Henshaw-Nuttall ni wọ́n bí ní Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù keje ọdún 1971 (19th July 1971),[1][2][3] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.Lọ́dún 2008 ó gbàmì ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award fún Òṣèré Tó Dára Jùlọ gẹ́gẹ́ bí olú-ẹ̀dá ìtàn.[4]

Ìgbé-ayé rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Kate ní ìpínlẹ̀ Cross River State, òun ni àkọ́bí nínú àwọn ọmọ mẹ́rin tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti gírámà ní ìpínlẹ̀ Èkó, ó kàwé ráńpẹ́ ni University of Calabarkí ó tó tẹ̀síwájú ní nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Lagos University Teaching Hospital (LUTH) ní ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tí ó ti kàwé gboyè àti ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ Medical Microbiology. Lẹ́yìn èyí, ó ṣiṣẹ́ ni ile ìwòsàn Ìjọba ìpínlẹ̀ Bauchi.[2]

Aáyan gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Lọ́dún 1993 ni ó kópa nínú sinimá àgbéléwò rẹ̀ àkọ́kọ́ tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ When the Sun Sets. [2] Henshaw has starred in over 45 Nollywood movies.[5] Nígbà tí ó di ọdún 2008, ó gbàmì ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Award fún Òṣèré Tó Dára Jùlọ gẹ́gẹ́ bí olú-ẹ̀dá ìtàn nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń' 'Stronger than Pain.[4] òun ni aṣojú polówó ìsebẹ̀ "Onga" lọ́wọ́lọ́wọ́ .[2] Henshaw is a judge on Nigeria's Got Talent.[6]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Above Death: In God We Trust (2003)
 • A Million Tears (2006)
 • My Little Secret (2006)
 • Stronger Than Pain (2007)
 • Show Me Heaven (2007)
 • Aremu The Principal (2015)[7]
 • Chief Daddy (2018) [8]
 • New Money (2018) [9]
 • The Ghost and the House of Truth (2019)[10]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Ige, Victoria (6 July 2011). "Kate Henshaw is 40!". Nigerian Entertainment Today (Lagos, Nigeria). http://thenetng.com/2011/07/06/kate-henshaw-is-40/. Retrieved 22 August 2012. 
 2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Profile of Henshaw-Nuttall at her Website". Archived from the original on 2018-07-24. Retrieved 2009-10-08.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 3. "2012: A Dramatic Year For Nigerian Artistes". P.M. News (Lagos, Nigeria). 28 December 2012. http://pmnewsnigeria.com/2012/12/28/2012-a-dramatic-year-for-nigerian-artistes/. Retrieved 24 January 2013. 
 4. 4.0 4.1 "AMAA 2008: List of Nominees and Winners". Retrieved 16 January 2010. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 5. "Filmography at IMDB". Retrieved 2009-10-08. 
 6. Nigeria's Got Talent Archived December 25, 2012, at the Wayback Machine.
 7. "'Aremu the Principal': Watch Kate Henshaw, Queen Nwokoye, Oyetoro Hafiz in trailer for new movie". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Retrieved 20 May 2015. 
 8. "Chief Daddy | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-13. 
 9. "New Money (2018 film)", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2019-10-24, retrieved 2019-11-13 
 10. "The Ghost and the House of Truth". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-28. Retrieved 2019-11-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)