Mike Ezuruonye
Mike Ezuruonye | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kẹ̀sán 1981
-09-21) Ipinle Eko, Ipinle Anambra, Naijiria |
Iṣẹ́ | Actor |
Mike Ezuruonye tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹsàn án ọdún 1982, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjị́ríà.
Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Mike ní ìlú Uzoakoli ní Ìpínlẹ̀ Abia wọ́n bi ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù Kẹsàn án ọdún 1982. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Federal Government College, ní ìlú Wukari, ní Ìpínlẹ̀ Taraba àti ilé-ẹ̀kọ́ Archbishop Aggey Memorial ní Ìpínlẹ̀ Èkó ṣáájú kí ó tó wọ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Nnamdi Azikiwe láti kọ́ nípa ìmọ̀ ìṣirò owó.[1][2] Ó ṣiṣẹ́ fúngbà díè nílé ìfowó-pamọ́ ṣáájú kí ó tó dara pọ̀ mọ́ eré orí-ìtàgé.[3] Ó ti kópa nínú àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan, wọ́n sì ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti "Òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ" látàrí ipa tí ó kó nínú eré Assassin nínú ayẹyẹ ti Africa Movie Academy Awards ọdún 2009.[4][5][6]Bákan náà ni wọ́n tún ti yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ ti "Òṣèrékùnrin tí ó peregedé jùlọ" níbi ayẹyẹ ti Africa Magic Viewers Choice Awards.[7]
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mike ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú aya rẹ̀ Nkechi Nnorom, wọ́n sì ti bímọ ọkùnrin tí wọ́n sọ ní Reynold Nkembuchim Ezuruonye.[8] He has a younger sister, Chichi, who is a Physician in the United Kingdom.[9][10]
Àwọn Àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Endless Passion (2005)
- Broken Marriage
- Beyond Reason
- Critical Decision
- Unforeseen (2005)
- Occultic Kingdom
- Desire (2008)
- Ropes of Fate (2010)
- Keep Me Alive (2008)
- Unforgivable (2014)[11]
- Calabash Part 1 & Part 2 (2014)
- The Duplex (2015)[12]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Mike Ezuruonye". Ibakatv. Archived from the original on 24 February 2015. Retrieved 26 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Actor Mike Ezuruonye". Take me to Naija. Retrieved February 28, 2015.
- ↑ Kemi Ashefon. "A FAN WANTED ME TO SIGN ON HER BRA — MIKE EZURUONYE". Nigeriafilms. Archived from the original on 3 April 2015. Retrieved 28 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "AMAA 2008: List of Nominees & Winners at ScreenAfrica.com". Archived from the original on 8 February 2010. Retrieved 17 January 2010.
- ↑ Orido, George (4 March 2011). "Mike Ezuruonye: The face of African movie". The Standard (Nairobi, Kenya). http://www.standardmedia.co.ke/InsidePage.php?id=2000030475&cid=482&story=Mike%20Ezuruonye:%20The%20face%20of%20African%20movie. Retrieved 9 March 2011.
- ↑ "AMAA Nominees and Winners 2009". African Movie Academy Award. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 9 March 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Adekunle Adedosu. "Mike Ezuronye, O.C Ukeje, others contest 2015 AMVCA award". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2014/12/mike-ezuronye-o-c-ukeje-others-contest-2015-amvca-award/.
- ↑ "Meet Actor Mike Ezuruonye and his Son (PHOTOS) | Akpraise.com". akpraise.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-09-03. Retrieved 2018-01-02.
- ↑ "Actor Mike Ezuruonye Walks His younger Sister Down the Aisle (See Photos) – Hype Nigeria". hypenigeria.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-01-02.
- ↑ "Mike Ezuruonye's Sister Becomes General Practitioner In UK" (in en-gb). Nigeriafilms.com. https://www.nigeriafilms.com/movie-news/92-nollywood-diaspora/29745-mike-ezuruonye-s-sister-becomes-general-practitioner-in-uk.
- ↑ Victor Enengedi (August 14, 2013). "Mike Ezuoronye makes Yoruba movie debut". http://thenet.ng/2013/08/mike-ezuruonye-makes-yoruba-movie-debut/. Retrieved February 28, 2015.
- ↑ "The Duplex: Mike Ezuruonye, Omoni Oboli scamper in House of Horror". The Tribune. Archived from the original on 4 March 2015. https://web.archive.org/web/20150304074916/http://www.tribune.com.ng/entertainment/item/30659-the-duplex-mike-ezuruonye-omoni-oboli-scamper-in-house-of-horror. Retrieved February 2, 2015.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pages with citations using unsupported parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Igbo male actors
- Nigerian male film actors
- Àwọn ènìyàn alààyè
- 21st-century Nigerian male actors
- Male actors in Yoruba cinema
- Nnamdi Azikiwe University alumni
- Male actors from Lagos
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1982