Lagos Cougars
Lagos Cougars | |
---|---|
Adarí | Desmond Elliot |
Olùgbékalẹ̀ | Emem Isong |
Àwọn òṣèré | |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Royal Arts Academy |
Olùpín |
|
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
Lagos Cougars jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2013 tó jẹ́ fíìmù ajẹmọ́fẹ̀ẹ́, èyí tíDesmond Elliot.[1] Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ wáyé ní ọjọ́ kẹta oṣù kejìlá ọdún 2013, ní Silverbird Galleria, Victoria Island.[2] Fíìmù náà dá lórí àwọn òṣìṣébìnrin mẹ́ta; Elsie (Monalisa Chinda), Aret (Uche Jombo) àti Joke (Daniella Okeke) pẹ̀lú ìlàkàkà wọn láti ṣalábàápàdé ìfẹ́.
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Monalisa Chinda bí i Elsie
- Uche Jombo bí i Aret
- Ifeanyi Kalu bí i Jite
- Daniella Okeke bí i Joke
- Shawn faqua bí i Vincent
- Benjamin Touitou bí i Lawrence
- Alex Ekubo bí i Chigo
Ìgbàwọlé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Fíìmù náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àríwísí. Nollywood Reinvented fún fíìmù yìí ní ìṣedára 18%, nítorí pé àhùnpọ̀ ìtàn náà ó dára tó, bẹ́ẹ̀ sì ni ìṣedarí rẹ̀ ò dára tó.[3]
YNaija bomi lu ọ̀rọ̀ ìfẹ́ tó wà láàárín Monalisa Chinda àti olólùfẹ́ rẹ̀ Benjamin Touitou. Wọ́n sọ ọ́ di mímọ̀ pé "Fíìmù Lagos Cougars panilẹ́rìn-ín ṣùgbọ́n àwàdá inú rẹ̀ ò bára mu".[4]
Sodas àti Popcorn sọ ọ́ nínú àríwísí wọn pé "...ìtàn náà ò kẹnú, kò sí ní ẹ̀yà kankan tí a lè fi wé...".[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Lagos Cougar". moviepencil.com. Archived from the original on 14 April 2014. Retrieved 8 May 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Lagos Cougar premieres". Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 8 May 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Lagos Cougar review on Nollywood Reinvented". Nollywood Reinvented. Retrieved 8 May 2014.
- ↑ "Lagos Cougar is Funny but not always for the right reasons". YNaija. Retrieved 8 May 2014.
- ↑ "Lagos Cougar review on Bella Naija". bellanaija.com. Retrieved 8 May 2014.