Alex Ekubo
Ìrísí
Alexx Ekubo | |
---|---|
Alexx Ekubo | |
Ọjọ́ìbí | Alex Ekubo-Okwaraeke 10 Oṣù Kẹrin 1986 Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | Law, University of Calabar |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Calabar |
Iṣẹ́ | Actor, model, Stylist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–present |
Alexx Ekubo (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Alex Ekubos-Okwaraeke; tí wọ́n bí ní ọjọ́ 10 oṣù April, ọdún 1986) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2] Óun ló gbégbá orókè nínú ìdíje Mr. Nigeria tó wáyé ní ọdún 2010. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Best Actor in a Supporting Role ní 2013 Best of Nollywood Awards fún ìkópa rẹ̀ nínú Weekend Getaway.[3][4][5]
Fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Secrets & Scandals
- Hope Bay
- Happy Family
- Tinsel
- AY's Crib
- Married to the Game
Àtòjọ àwọn fíìmù àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Aina (2011)
- Weekend Getaway (2012)
- True Citizens (2012)
- In the Cupboard (2012)
- Dream Walker (2013)
- Keeping my Man (2013)
- Lagos Cougars (2013)
- Champagne (2014)
- Single, Married and Complicated (2014)
- Ifedolapo (2014)[6]
- Gold Diggin (2014) (pẹ̀lú Yvonne Nelson àti Rukky Sanda)
- Undercover Lover (2015)
- All that Glitters (2015)
- The First Lady (2015) (pẹ̀lú Omoni Oboli)
- Gbomo Gbomo Express (2015)
- Death Toll (2015)[7]
- Entreat (2016)
- The Other Side of the Coin (2016)
- Diary of a Lagos Girl (2016)
- Wife Material (2017)[8]
- A Man for the Weekend (2017) (pẹ̀lú Syndy Emade)
- Catcher (2017)
- 3 is a Crowd (2017)[9][10]
- Hot Girl Next Door (2018)
- Switch (2018)
- Power of 1 (2018)
- The American King: As told by an African Priestess (2019)
- Bling Lagosians (2019)
- Zero Hour (2019)
- Your Excellency (2019)
- 72 hours (2019)
- Soft Work (2020)
- Son of Mercy (2020)
- The Blood Covenant
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Fíìmù | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2012 | Best of Nollywood Awards | Most Promising Actor | In The Cupboard | Gbàá | |
2013 | Golden Icons Academy Movie Awards | Best Supporting Actor | Weekend Getaway | Gbàá | |
Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actor | Gbàá | |||
2014 | Screen Nation Awards | Favourite Male Emerging Screen Talent (African) | Himself | Gbàá | [11] |
2017 | Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Lead role – English | Inikpi | Wọ́n pèé | [12] |
2020 | 2020 Best of Nollywood Awards|Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Supporting Role (English) | The Bling Lagosians | Gbàá | [13] |
Best Kiss in a Movie | Wọ́n pèé | [14] | |||
2021 | Net Honours | Most Popular Actor | Gbàá | [15] |
Àwọn ìọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "I don't have anything to prove to anyone". bellanaija.com. Retrieved 25 April 2014.
- ↑ Kayode, Dami (2021-08-27). "'I feel bad for him' - Reactions as Alexx Ekubo step out amidst breakup drama". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-12.
- ↑ "Alex Ekubo wins Screen Nation Award". Archived from the original on 24 July 2020. Retrieved 25 April 2014.
- ↑ "Alex Ekubo profile at". imdb.com. Retrieved 25 April 2014.
- ↑ "Genevieve Magazine interviews Alex Ekubo". genevieveng.com. Archived from the original on 2014-04-26. Retrieved 25 April 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Tope Osoba gives Alex Ekubo first Yoruba movie role". The Vanguard. July 15, 2014. http://www.vanguardngr.com/2014/07/tope-osoba-gives-alex-ekubo-first-yoruba-movie-role/. Retrieved August 11, 2015.
- ↑ "'Death Toll': Alexx Ekubo, IK Ogbonna, Mike Godson star in new movie". 199News. Ayebusiwa Victor. Archived from the original on 25 May 2015. Retrieved 25 May 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Wife Material - iBAKATV | Home for Nollywood Movies". ibakatv.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-02-23. Retrieved 2019-02-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "3 IS A CROWD now playing on iROKOtv!". irokotv blog (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-28. Archived from the original on 9 December 2021. Retrieved 2019-02-23. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "3 IS A CROWD". Talk African Movies (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-31. Retrieved 2019-02-23.
- ↑ "Alex Ekubo wins SNA". dailytimes.com. Retrieved 25 April 2014.
- ↑ "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-11-23. Retrieved 2021-10-07.
- ↑ Augoye, Jayne (2020-12-07). "BON Awards: Laura Fidel, Kunle Remi win Best Kiss (Full List of Winners)" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Augoye, Jayne (2020-12-02). "2020 BON: Here are 5 nominees for ‘Best Kiss’ category" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-21. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)