Syndy Emade
Syndy Emade (ti a bi gege bi Elone Synthia Emade ni ojo kankanlelogun osu kankanla odun 1993) je osere, awose ati agbe ere jade omo ilu Cameroon. Oje asoju burandi fun InstaVoice Celeb.[1][2] Ohun ni oda ile ise Blue rain entertainment.[3][4] Awon ere ti oti gbe jade je A Man For The Weekend and Rose on The Grave. O jade ninu ere Nigeria Nollywood ni odun 2016 ninu ere "Why I Hate Sunshine"[5] Ni odun 2017, won ko oruko e kale gegebi osere keji ti o sise ju ni ilu Cameroon, awon agbere jade ori ero ayelujara Njoka Tv fun ile Áfríkà[6] Won fun ni ami eye osere obirin ti o dara julo ni ile cameroon, ni ami eye Scoos Academy ni odun 2017.[7] O gba ami eye yeye ini ti Cameroon ni odun 2014.[8]
Iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ere ti Emade ko se ni ere "Obsession" ti o jade ni odun 2010[9] ohun ni alaga ati oludasile Blue Rain Entertainment. Ni odun 2017 o gbe ere A Man For The Weekend jade eleyi ti oni osere Nollywood Alexx Ekubo ninu e.[10]
Asayan Ere
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Odun 2017
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- A Man For The Weekend
Odun 2016
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Bad Angel (jara)
- Soldier wife
- House mate
- Smokesscreen
- Before you say yes
- Chaising tails
Odun 2015
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Die Another Day
- A Kiss from Rose
- Chaising tails
Odun 2014
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Why I hate sunshine
- Rose on the grave
- Different kind of men (2013)
- Pink poison with Epule Jeffrey (2012)
- Entangled
- Obsession (2010)
Awards ati ti idanimọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Odun | Eye | Ẹka | Olugba | Esi |
---|---|---|---|---|
Ọdun 2014 | Miss Ajogunba Africa | Cameroon | rowspan="2" | Gbàá |
2017 | Eye Scoos Academy | Osere ti o dara ju | Funrararẹ| Gbàá |
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Syndy Emade Joins Yvonne Nelson as The Faces Of Orange Instavoice Celeb Africa". cameroonbeauty. 23 April 2017. Archived from the original on 2019-09-24. https://web.archive.org/web/20190924204038/http://www.cameroonianbeauties.com/alex-ekubo-syndy-emade/. Retrieved 12 August 2017.
- ↑ Henriette. "Cameroon's Syndy Emade Becomes The New Face For InstaVoice Celeb By Orange". www.henrietteslounge.com. Archived from the original on 5 October 2018. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ Henriette. "Cameroon's Syndy Emade Becomes The New Face For InstaVoice Celeb By Orange". www.henrietteslounge.com. Archived from the original on 5 October 2018. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ "Nexdim Empire » Blue Rain Entertainment". Nexdim Empire. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Syndy Emade: Actress talks film industry in Cameroon, challenges as a female filmmaker, getting into character". pulse.ng. Archived from the original on 14 August 2017. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ "TOP FIVE MOST ACTIVE CAMEROONIAN ACTRESSES IN 2017". njokatv.com. 18 April 2017. Archived from the original on 15 June 2017. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ "Is Syndy Emade Cameroon’s best actress? – Dcoded TV". dcodedtv.com. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ mbenwohasaba (11 September 2014). "Miss Heritage Cameroon 2014 is Syndy Emade". kamer360.com. Archived from the original on 5 October 2018. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ "Syndy Emade, La belle aux trois casquettes - Culturebene". culturebene.com. 25 September 2016. Retrieved 14 August 2017.
- ↑ "Syndy Emade borrows Alexx Ekubo for new movie "A Man For The Weekend" – Dcoded TV". dcodedtv.com. Retrieved 14 August 2017.