Rukky Sanda
Ìrísí
Rukayat Akinsanya (bíi ni kẹtàlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1984[1]) tí orúkọ inagi rẹ̀ jẹ́ Rukky Sanda jẹ́ òṣèré àti adarí eré ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2][3][4] Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní ọdún 2004 nígbà tí ó ṣí wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Lagos State University.[5] Óun àti òṣèré Bọ́láńlé Nínálowó jẹ́ mọ̀lẹ́bí.[6]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lethal Woman (2008)[7]
- Obscure Motives (2009)
- Lovelorn (2012)
- Miami Heat (2012)
- Keeping My Man (2013)
- White Chapel
- The Seekers
- Legal War
- Campus Love
- Keeping my Man (2013)[7]
- Gold Diggin
- What's Within
- The Relationship (2016)
Àwọn Ìtọ́kàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Rukky Sanda, NAIJ, Retrieved 22 September 2016
- ↑ "I’m no longer bothered by criticism – Rukky Sanda". punchng.com. Archived from the original on August 26, 2014. Retrieved 21 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Rukky Sanda’s love for tattoos". punchng.com. Archived from the original on August 26, 2014. Retrieved 21 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Rukky Sanda shows off in Range Rover Evoque". punchng.com. Archived from the original on August 23, 2014. Retrieved 21 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Saturday Celebrity Interview: She’s not a Rookie! Nollywood Actress Rukky Sanda is Breaking New Grounds & Stepping on to Greater Heights". Bella Naija. http://www.bellanaija.com/2012/10/06/bn-saturday-celebrity-interview-shes-not-a-rookie-nollywood-actress-rukky-sanda-is-breaking-new-grounds-stepping-on-to-greater-heights/. Retrieved November 22, 2014.
- ↑ Gists, Naija (2017-12-06). "Bolanle Ninalowo: My Cousin, Rukky Sanda Gave Me My First Movie Role After My Record Label Failed". NaijaGists.com - Nigerian Nollywood Entertainment News & Motivation Blog Business Ideas, Natural Health & Relationship Tips (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-16.
- ↑ 7.0 7.1 Rukky Sanda, NAIJ, Retrieved 22 September 2016