Jump to content

Tinsel (TV series)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tinsel
Fáìlì:Tinsel title screen.jpg
GenreSoap opera[1]
Created byYinka Ogun[2]
Written byYinka Ogun
Kemi Adesoye
Uju Asika
Tunde Babalola
Directed byTope Oshin Ogun (2008 - 2013)
Alex Mouth (2008 - 2010; 2012 - 2014)
Efe Aiyeteni (2008 - 2009 )
John Njamah (2008 - 2009 )
Victor Aghahowa (2010 - 2014 )
Ben Chiadika (2010 - )
George Sunom Kura (2012 - )
Tolu Ajayi (2009 - 2010)
StarringVictor Olaotan
Funlola Aofiyebi-Raimi
Ireti Doyle
Damilola Adegbite
Chris Attoh
Funmi Holder
Udoka Oyeka
Osas Ighodaro
Gbenro Ajibade
Linda Ejiofor
Bimbo Manuel
Oghenekaro Itene
Matilda Obaseki
Tomi Odunsi
Leonora Okine
Kalu Ikeagwu
Lizz Njagah
Abiola Segun Williams
Anne Njemanze
Florence Uwaleke
Ike Okechukwu
Nini Mbonu
Yul Edochie
Alex Okoroji
Samuel Abiola Robinson
Fisayo Ajisola
Adesewa Josh
Chris Okagbue
Wale Dizzy Akinjogbin
Country of originNigeria
Original language(s)English
No. of seasons16
No. of episodes3600
Production
Executive producer(s)Jaiye Ojo[1]
Producer(s)Rogers Ofime[3]
Lemmy Adebule
Femi Odugbemi [1]
Production location(s)Lagos, Lagos State, Nigeria
Camera setupMulti-camera[1]
Running time25 minutes
Release
Original networkM-Net
Original release1 Oṣù Kẹjọ 2008 (2008-08-01) – present

Tinsel jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kẹfà, ọdún 2008.[1] Ní ọjọ́ 23 May, ọdún 2013, wọ́n ṣàfihàn 1000th episode eré náà lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán.[2] Ó jẹ́ fíìmù àgbéléwò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán tó gbajúmọ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4] Ní ọjọ́ 21 Jan, ọdún 2021, wọ́n ṣàfihàn 3000th episode eré náà.

Àhunpọ̀ ìtàn ní ṣókí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àhunpọ̀ ìtàn Tinsel wáyé láàárín ilé-iṣé aṣàgbéjáde fíìmù méjì ọ̀tọ̀tọ̀ tí wọ́n di orogún ara wọn. Àkọ́kọ́ ni: Reel Studios, èyí ti Fred Ade-Williams (Victor Olaotan) ṣe ìdásílẹl rẹ̀, àti Odyssey Pictures, èyí tí Brenda "Nana" Mensah (Funmilola Aofiyebi-Raimi) jẹ́ olùdarí fún.[5] Tinsel jẹ́ eré ajẹ́mọ́fẹ̀ẹ́, ajẹmẹ́tàn àti àlùyọ. Fíìmù náà bẹ̀rẹ̀ apá kẹjọ ní ọjọ́ 25 May, ọdún 2015.

  • Matilda Obaseki gégé bí i Angela Dede
  • Funlola Aofiyebi-Raimi gégé bí i Brenda Nana Mensah (2009 – present)
  • Iretiola Doyle gégé bí i Sheila Ade-Williams
  • Linda Ejiofor gégé bí i Bimpe
  • Kalu Ikeagwu gégé bí i Masters
  • Anne Njemanze gégé bí i Sankey
  • Ashionye Michelle Raccah gégé bí i Monica Ade-Williams
  • Funmi Holder gégé bí i Amaka Ade-Williams
  • Tomi Odunsi gégé bí i Salewa
  • Yewande Lawal gégé bí i Shoshanna
  • Dozie Onyiriuka gégé bí i Freddy
  • Abiola Segun-Williams gégé bí i Titi (láti ọdún 2008 títí di báyìí)
  • Florence Uwaleke gégé bí i Ene (láti ọdún 2008 títí di báyìí)
  • Ike Okechukwu gégé bí i Chuks Obi
  • Charles Ujomu gégé bí i Frank (láti ọdún 2008 títí di báyìí)
  • Oghenekaro Itene gégé bí i Wedding Planner
  • Ibrahim Suleiman gégé bí i Damini
  • Nini Mbonu gégé bí i Vicky
  • Jumoke Bello gégé bí i Peju
  • Ifeanyi William gégé bí i Obiora
  • Paul Barnaby Ephraim "Jaypaul" gégé bí i Adu

Fíìmù Tinsel Fíìmù wà ní ìpẹle ìṣàgbéjáde fún àádọ́rùn-ún oṣù.[1] Àwọn òṣèré tọ́ wá fún àyẹ̀wò láti ṣe olú ẹ̀dá-ìtàn tó ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta, kí wọ́n ṣẹ̀ tó yan Victor Olaotan láti ṣe é.[6] Ní oṣù June 2013, iye owó tí wọ́n fi ń ṣàgbéjáde fọ́nrán oníṣẹ̀ẹ́jú kan tó 900 dollars, tí iye àpapọ̀ náà jẹ́ four billion naira.[2] Studio kan ní Ojota, ní Ìpínlẹ̀ Èkó ni wọ́n ti ya fọ́nrán náà, títí di oṣù March, ọdún 2013 kí iná tó ba agbègbè náà jẹ. Láti ìgbà náà ni wọ́n ti ń ya fọ́nrán náà ni agbègbè kan ní Ikeja, ní Ìpínlẹ̀ Èkó bákan náà.[2]

Àmì-ẹ̀yẹ àti yíyàn fún àmì-ẹ̀yẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsòrí Àbájáde Ìtọ́kasí
2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards Longest running TV show in Africa Gbàá [7]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 "Tinsel: The journey so far". Vanguard. 17 September 2011. Retrieved 30 September 2013. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 Alonge, Osagie (3 June 2013). "NET SPECIAL REPORT: Tinsel gulps N4bn in four years". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 30 September 2013. 
  3. Bada, Gbenga (July 2017). "Rogers Ofime: NANTAP honours Tinsel producer". PulseNG. Retrieved 5 April 2017. 
  4. Balogun, Hazeez (May 2013). "Tinsel, a return to the golden age of TV drama". Daily Independent. Archived from the original on 11 October 2013. Retrieved 30 September 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Arogundade, Funsho (24 May 2013). "M-Net’s Tinsel Hits Episode 1,000". P.M. News. Retrieved 30 September 2013. 
  6. "Tinsel is Nigeria’s best TV production —Victor Olaotan". Nigerian Tribune. 10 August 2013. Retrieved 1 October 2013. 
  7. "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-61452928.