Tunde Babalola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tunde Babalola
Ọjọ́ìbíEngland
Orílẹ̀-èdèNigerian / British
Iléẹ̀kọ́ gígaObafemi Awolowo University
Iṣẹ́Screenwriter
Ìgbà iṣẹ́1997–present

Tunde Babalola jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó sì jẹ́ akọ̀tàn fún fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán ti ilẹ̀ Britain.[1] Ó gbajúmọ̀ fún àwọn fíìmù bíi Last Flight to Abuja, Critical Assignment, October 1 àti Citation tí ó ti kọ,[2] àti àwọn fíìmù ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán bíi Tinsel The Bill àti In Exile. Ó kópa nínú fíìmù ọdún 2001 kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Deep Freeze, àmọ́ ó sọ ọ́ di mímọ̀ pé ìyẹn kọ́ ni iṣẹ́ tí òun yàn láàyò.[3]

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bi sí ìlú England, ibẹ̀ ló sì dàgbà sí. Lẹ́yìn náà, ó kó lọ sí Nàìjíríà pẹ̀lú àwọn òbí àti àbúrò rẹ̀. Bàbá rẹ̀ jẹ́ oníṣirò owó, nígbà tí ìyá rẹ̀ ń ṣiṣẹ́ ní Central Bank. Lábẹ́ ìtọ́jú Ẹ̀gbọ́n bàbá rẹ̀, ìyẹn Lieutenant-Colonel ní ẹgbẹ́ ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, Babalola forúkọ sílẹ̀ láti dara pọ̀ mọ́ Nigerian Defence Academy (NDA). Àmọ́ ìyá rẹ̀ ò gbà á láyè. Nítorí náà, ó wọlé sí Obafemi Awolowo University láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa iṣẹ́ tíátà.[4]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Film Role Genre Ref.
1997 The Bill writer TV series
1997 True to Life Player writer TV series
1997 Crime of a Lesser Passion writer TV series
1997 Armed and Dangerous writer TV series
1998 In Exile writer TV series
1998 One Man, Two Faces writer TV series
2002 Single Voices writer TV series
2002 Deep Freeze Actor: Shockley Film
2004 Critical Assignment screenplay, writer Film [5]
2008 Life in Slow Motion writer Short film
2011 Maami screenplay Film
2012 Last Flight to Abuja story Film
2012 The Meeting writer Film
2014 October 1 script writer Film
2016 The CEO writer Film
2018 The Eve (2018 film) writer Film
2019 Mokalik (Mechanic) writer Film [6]
2020 Citation writer Film
2021 La Femme Anjola writer Film [7]
2024 Funmilayo Ransome-Kuti (2024) writer Film .[8][9]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Actress, Anne Njemanze Steps out with Sneakers on Native Attire". modernghana. Retrieved 11 October 2020. 
  2. "Tunde Babalola: Screenwriter, story". MUBI. Retrieved 11 October 2020. 
  3. "Tunde Babalola's interview with The Nation". thenationonlineng. Retrieved 14 April 2023. 
  4. "As a scriptwriter, I faced rejection for three years in UK–Tunde Babalola". Vintage Press Limited. Retrieved 11 October 2020. 
  5. "Critical Assignment". fandango. Retrieved 11 October 2020. 
  6. "Movie Review: Kunle Afolayan's 'Mokalik' thrives on memory, not viewer satisfaction". premiumtimesng. Retrieved 11 October 2020. 
  7. Obioha, Vanessa (19 March 2021). "Review: Different Shades of Entrapment in 'La Femme Anjola'". This Day (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 April 2021. 
  8. "FULL LIST: Funmilayo Ransome-Kuti biopic wins big at 2023 AFRIFF Awards". The Cable Lifestyle. Retrieved 17 November 2023. 
  9. "AFRIFF Awards: Bolanle Austen-Peters celebrates as she wins Best Feature Film award". Gist Reel. Retrieved 12 November 2023.