Last Flight to Abuja
Ìrísí
Last Flight to Abuja | |
---|---|
Adarí | Obi Emelonye |
Olùgbékalẹ̀ |
|
Òǹkọ̀wé |
|
Àwọn òṣèré | |
Orin | Luke Corradine |
Ìyàwòrán sinimá | James M. Costello |
Olóòtú | Ben Nugent |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Nollywood Film Factory |
Olùpín | Netflix |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 81 min |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English |
Ìnáwó | ₦40 million[1] |
Owó àrígbàwọlé | ₦57,050,000 (domestic gross)[1] |
Last Flight to Abuja jẹ́ fíìmù 2012 Nàìjíríà àjálù tí a kọ nípasẹ̀ Tunde Babalola, tí Obi Emelonye ṣe àti mú jáde, tí Omotola Jalade Ekeinde, Hakeem Kae-Kazim àti Jim Iyke ṣe. Tí a yàwòrán ní Ìlú Èkó, fíìmù náà gba àwọn yíyan àbùn márùn-ún ní ọdún 2013 Africa Movie Academy Awards, tí ó borí ní ẹ̀ka “Fíìmù tí ó dára jùlọ nípasẹ̀ orísun Áfíríkà kan ní ilẹ̀ òkèèrè”. [2][3][4] Ní ọjọ́ márùn-dín-lógún, oṣù kẹfà ọdún 2020, 'Last Flight to Abuja' bẹ̀rẹ̀ àfihàn lórí Netflix ní ọdún mẹ́jọ lẹ́hìn tí ó kọ́kọ́ ṣe àfihàn ní Ìlú Lọ́ndọ́nù. [5]
Àwọn Òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Omotola Jalade Ekeinde - Suzie
- Hakeem Kae-Kazim - Adesola
- Ali Nuhu - Dan
- Jim Iyke - David
- Anthony Monjaro - Aircraft captain
- Uru Eke - Air hostess
- Tila Ben - Passenger
- Jide Kosoko - Chief Nike
- Celine Loader - Captain Seye
- Uche Odoputa - Efe
- Jennifer Oguzie - Yolanda
- Samuel Ajibola
- Ashaju Oluwakemi
- Nneka J. Adams
Ṣíṣe Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní àsìkò tí ó ń ṣiṣẹ́ fíìmù yìí, Emelonye ní láti bá àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀, àwọn ilẹ́-ìfowópamọ́, àti àwọn òṣìṣẹ́ aláṣẹ wọ̀ ní pápá-ọkọ̀ òfurufú Murtala Muhammed tó wà nílùú Èkó.[6]
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Kay, Chris (13 August 2013). "Moviemakers Beg Banks for Cash as Nollywood Goes Global". Bloomberg. https://www.bloomberg.com/news/2013-08-12/moviemakers-beg-banks-for-cash-as-nollywood-goes-global.html.
- ↑ Arogundade, Funsho (16 March 2013). "Emelonye's ' Last Flight To Abuja' Tops AMAA Nominations". P.M. News Nigeria. http://pmnewsnigeria.com/2013/03/16/emelonyes-last-flight-to-abuja-tops-amaa-nominations.
- ↑ "Africa Movie Academy Awards (AMAA) Winners 2013". Africa Movie Academy Awards. Archived from the original on 31 May 2013. Retrieved 2 June 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Full List of Nominees for 2013 Africa Movie Academy Awards". African Spotlight (Lagos, Nigeria). 18 March 2013. Archived from the original on 7 November 2016. https://web.archive.org/web/20161107155015/http://africanspotlight.com/2013/03/18/full-list-of-nominees-for-2013-african-movie-academy-awards/.
- ↑ "Obi Emelonye talks lessons from making Nollywood classics [Pulse Interview"]. http://www.pulse.ng/entertainment/movies/obi-emelonye-talks-lessons-from-making-nollywood-classics-pulse-interview/dfdg5fq/2020/03/18/.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Kay, Chris; Spillane, Chris (13 December 2013). "Nollywood comes of age". Oman Tribune. Archived from the original on 13 December 2013. Retrieved 25 May 2019.
Àwọn ẹ̀ka:
- Template film date with 2 release dates
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Pages with citations using unsupported parameters
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from October 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links