Ali Nuhu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán Ali Nuhu níbi ayeye AMVCA 2020
Ali Nuhu
Ọjọ́ìbíAli Nuhu Mohammed
ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Southern California
Iṣẹ́òṣèré
Parents
  • Nuhu Poloma (father)
  • Fátima Karderam Digema (mother)

Ali Nuhu Mohammed (táabì ni ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù kẹta, ọdún 1974) jẹ́ òṣèré ará Nàìjíríà àti olùdarí.[1]Ó má ń ṣe ère Haúsá àti ère Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn òní ròyìn má ń pè ní "king of kannywood" tàbí "sarki".Kannywood ni orúkọ ilé ìṣe fímù Hausa.[2] Nuhu ti kópa nínú àwọn ère Nollywood Àti Kannywood tí ó tó Ẹ̀dẹ́gbẹ́ta filmu. [3]

Early Life[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nuhu jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Maiduguri, Borno State ní Àríwá Ìwọ̀ Òrùn. Bàbá rẹ̀, Nuhu Poloma jẹ́ ọmọ Ìlú Balanga ni ìpínlẹ̀ Gombe àti Ìyá rẹ̀, Fátima Karderam Digema jẹ́ ọmọ ìjọba àgbègbè Bama ni ìpínlè Borno.[4]Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Jos àti Kano. Ó lọ sí Fáṣítì Jos, níbi tí ó ti gba Oyè ẹ̀kọ́ ní Arts.Ó ṣe Ẹ̀sìn orílè èdè ni Ìbàdàn, Ìpínlẹ̀ Oyo. Ó padà lọ sí University of Southern California fun Ẹ̀kọ́ nínu ṣíṣe fíìmù àti àwọn ọ̀nà sinimá.[5]

Àkójọ̀pó Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Ali Nuhu returns to school". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
  2. "An karrama Ali Nuhu da Adam Zango a London". bbc.com/hausa. BBC. Retrieved 13 October 2017.
  3. "Ali Nuhu, Adam Zango, others win awards in London". premiumtimesng.com. Premium Times. Retrieved 13 October 2017.
  4. https://www.voahausa.com/a/a-39-2005-08-06-voa1-91733284/1370189.html
  5. https://ab-tc.com/biography-of-ali-nuhu-career-awards-and-net-worth/