Èdè Lárúbáwá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí

Àdàkọ:Cleanup

Arabic
العربية al-ʿarabīyah
Arabic albayancalligraphy.svg
Ìpè /alˌʕaraˈbiːja/
Sísọ ní Primarily in the Arab states of the Middle East and North Africa;
liturgical language of Islam.
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ Approx. 280 million native speakers[1] and 250 million non-native speakers[2]
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọ Arabic alphabet, Syriac alphabet (Garshuni), Bengali script [1] [2]
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní Official language of 25 countries, the third most after English and French[3]
Àkóso lọ́wọ́

Algeria: Supreme Council of the Arabic language in Algeria
Egypt: Academy of the Arabic Language in Cairo
Iraq: Iraqi Academy of Sciences
Jordan: Jordan Academy of Arabic
Libya: Academy of the Arabic Language in Jamahiriya
Morocco: Academy of the Arabic Language in Rabat
Sudan: Academy of the Arabic Language in Khartum
Syria: Arab Academy of Damascus (the oldest)

Tunisia: Beit Al-Hikma Foundation
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1 ar
ISO 639-2 ara
ISO 639-3 ara – Arabic (generic)
(see varieties of Arabic for the individual codes)
[[File:
Map of Majority and Minority Arabic Speakers

Map of the Arabic-speaking world.
Green: Majority Arabic Speakers.
Light Green: Minority Arabic Speakers.|300px]]

Ède Lárúbáwá tabi ede Araabu Ara èdè Sèmítíìkì ni èdè Àrábíìkì (Arabic (Èdè Lárúbááwá)). Àwon tí ó ń so ó tó mílíònù lónà igba gégé bí èdè abíníbí ní àríwá Aáfíríkà àti ìlà-oòrùn-gúsù Eésíà (Asia). Àìmoye ènìyàn tí a kò lè fi ojú da iye won ni ó ń so èdè yìí gégé bí èdè kejì, ìyen èdè àkókún-teni ní pàtàkì ní àwon orílè-èdè tí èsìn Mùsùlùmú ti gbilè. Àwon tí ó lo se àtìpó ní pàtàkì ní ilè faransé náà máa ń so èdè yìí. Ibi tí àwon tí ó ń so èdè yìí pò sí ju ni Algeria, Egypt, Iraq, Morocco, Saudi Arabia, Sudan, Syria, Tunisia àti Yeman. Àwon èka-èdè re kan wà tí ó jé ti apá ìwò-oòrùn tí àwon kan sì jé ti ìlà-oòrùn. Èdè tí a fi ko kòráànù sílè ni a ń pè ní ‘Classical’ tàbí ‘Literary Arabic’. Èdè mímó ni gbogbo mùsùlùmú àgbáyé tí ó tó egbèrún ó lé ogórùn-ún mílíònù ní àgbáyé (1, 100 million) nínú ètò ìkànìyàn 1995 ni ó mo èdè ‘Classical Arabic’ yìí. Olórí èka-èdè Lárúbáwá wà tí ó sún mó èyí tí wón fi ko Kòráànù. Eléyìí ni wón fi ń ko nnkan sílè. Òun náà ni wón sì máa ń lo dípò àwon èka-èdè Lárúbáwá. Púpò nínú àwon tí ó ń so èka-èdè lárúbáwá yìí ni wón kò gbó ara won ní àgbóyé. Méjìdínlógbòn ni àwon álúfábéètì èdè Lárúbááwá. Apé òtún ni wón ti fi ń kòwé wá sí apá òsù Yàtò sí álúfáséètì ti Rómáànù, ti Lárúbáwá ni àwon ènìyàn tún ń lò jù ní àgbáyé. A ti rí àpeere pé láti nnkan bíi séńtérì kéta ni a ti ń fi èdè Lárúbáwá ko nnkan sílè. Nígbà tí èsìn mu`sùlùmí dé ní séńtúrì kéje ni òkosílè èdè yìí wá gbájúgbajà. Wón tún wá jí sí ètò ìkosílè èdè yìí gan-an ní séńtúrì kókàndínlógún nígbà tí ìkosílè èdè yìí ní ìbásepò pèlú àwon ará. Ìwò-oòrùn Úróòpù. Ní pele-ń-pele ni èdè yìí pín sí (ìyen ni pé eléyìí tí olówó ń so lè yàtò sí ti tálíkà tàbí kí ó jé pé eléyìí tí obìnrin ń lò lè yàtò sí ti okùnrin).  1. Procházka, 2006.
  2. Ethnologue (1999)
  3. Wright, 2001, p. 492.