Jide Kosoko
Ìrísí
Ọmọba Jídé Kòsọ́kọ́ jẹ́ ògbónta òṣèré àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.[1][2][3][4][5]
Ìgbà èwé àti ìrínàjò iṣẹ́ rẹ̀.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bíi ní Ọjọ́ kejìlá Oṣù kínín Ọdún 1954 ní ìlú èkó sí ìdílé ọlọ́ba Kosoko ti erékùṣù èkó. Ó kàwé nípa okùn-òwò ní Yaba College of Technology.[6] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe bí ọmọdé òṣèré ní ọdún 1964 ní eré Makanjuola tí wọ́n máa ṣàfihàn rẹ̀ ní amóhùnmáwòran. Ó ti kópa nínú oríṣiríṣi eré ti Nollywood ní èdè Yorùbá àti ní èdè gẹ̀ẹ́sì.[7]
Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó fẹ́ ìyàwó méjì; Karimat àti Henrietta[6] pẹ̀lú àwọn ọmọ àti ọmọọmọ.[2]
Àwọn eré tí ó ti ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Department (2015)[8]
- Gidi Up (2014) (TV Series)
- Doctor Bello (2013)
- The Meeting (2012)
- Last Flight to Abuja (2012)
- I'll Take My Chances (2011)
- The Figurine (2009)
- Jenifa
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "How I survived car crash – Jide Kosoko" Archived 2014-08-02 at the Wayback Machine.. punchng.com.
- ↑ 2.0 2.1 "I would have been disappointed if none of my children became an actor – Jide Kosoko" Archived 2014-08-12 at the Wayback Machine.. punchng.com.
- ↑ "Jide Kosoko reveals he has diabetes". dailypost.ng.
- ↑ "My life as Jide Kosoko’s daughter—Abidemi Kosoko". tribune.com.ng.
- ↑ "Dad doesn’t know how to discipline kids— Jide Kosoko’s daughter" Archived 2014-08-11 at the Wayback Machine.. punchng.com.
- ↑ 6.0 6.1 Yetunde Bamidele. "Nollywood Actor, Jide Kosoko talks about life at the age of 60". http://www.naij.com/58328.html. Retrieved February 24, 2015.
- ↑ "Jide Kosoko: A true actor at 60". Daily Independent. January 18, 2014. http://dailyindependentnig.com/2014/01/jide-kosoko-a-true-actor-at-60/. Retrieved February 24, 2015.
- ↑ "'The Department' Watch Osas Ighodaro, OC Ukeje, Majid Michel in trailer" Archived 2017-03-20 at the Wayback Machine..