Omotola Jalade Ekeinde

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Ọmọ́tọ́lá Jaládé-Èkéìndé
Àdàkọ:Postnominals
Omotola Jalade Ekeinde WEF 2015.png
Omotola at the World Economic Forum in 2015
Ọjọ́ìbíOmotola Jalade
7 Oṣù Kejì 1978 (1978-02-07) (ọmọ ọdún 42)
Lagos State, Nigeria
IbùgbéLagos, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ míràn"Omo Sexy"
Omotola Jolade Ekeinde
Omotola Jalade
Omotola Ekeinde
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian (1978–present)
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́actress, singer, former model
Ìgbà iṣẹ́1995–present
Olólùfẹ́
Capt. Matthew Ekeinde (m. 1996)
Àwọn ọmọPrincess Ekeinde (b. 1997)[1]
M.J Ekeinde (b. 1998)[1]
Meraiah Ekeinde (b. 2000)[1]
Michael Ekeinde (b. 2002)[1]
Parent(s)Oluwatoyin Jalade (mother)
Oluwashola Jalade (father)
Signature
omosexy

Ọmọ́tọ́lá Jaládé-Èkéìndé (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù kejì ọdún 1978) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò, olórin àti Afowó-ṣàánú ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ỌDÚN 1995 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò, láti àkókò náà, ó ti kópa nínú sinimá àgbéléwò tí ó ti ju ọ̀ọ́dúnrún lọ. Bẹ́ẹ̀ náà, àìmọye àmìn ẹ̀yẹ ló ti gbà lórí à ń ṣeré sinimá àgbéléwò yìí. Bí ó ṣe ń ṣe sinimá àgbéléwò bẹ́ẹ̀ ló ń kọrin ìgbàlódé. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olólùfẹ́ ní wọ́n sìn ń tẹ́lẹ̀ lórí àwọn ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 Aiki, Damilare (7 August 2013). "Beautiful Family! See Omotola Jalade-Ekeinde’s Children at the "AGN Honours Omotola" Event in Lagos". Bellanaija. Retrieved 2 May 2014.