Ramsey Nouah

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ramsey ninu fiimu ti akole re je gbomo gbomo
Ramsey Nouah
Ọjọ́ìbíRamsey Tokunbo Nouah
16 July 1973
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria

Ramsey Tokunbo Nouah, (ojoibi 16 July 1973) je osere omo Naijiria to gbajumo ni Nollywood.