Chris Attoh
Chris Attoh (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Christopher Keith Nii Attoh; tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù karùn-ún, ọdún 1979) jẹ́ òṣèrékùnrin, olùdarí fíìmù, olóòtú ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán àti aṣàgbéjáde eré. Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí "Kwame Mensah" nínú fíìmù ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó lọ sí New York Film Academy, Achimota School àti Accra Academy. Ní Accra Academy yìí, lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ẹgbẹ́ rẹ̀ ni oníṣòwò àti olóòtú ètò rédíò tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Nathan Adisi. Lẹ́yìn náà ni ó lọ sí KNUST, níbi tí ó ti gboyè ẹ̀kọ́ Bachelor of Art láti kékọ̀ọ́ nípa fífí ọ̀dà sí àwòrán. Ó lọ sí ìlú London láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa Banking and Securities.[4]
Ṣíṣe olóòtú ètò níbi ayẹyẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó dìjọ ṣe olóòtú ètò ní ayẹyẹ Vodafone Ghana Music Awards ní ọdún 2006 pẹ̀lú Naa Ashorkor àti DJ Black.[5] Òun sì ni olóòtú ètò F.A.C.E List Awards ní New York City ní ọdún 2014 pẹ̀lú Sandra Appiah.[6]
Ní ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ kìíní oṣụ̀ kẹfà ọdún 2024, ó ṣe olóòtú ètò Telecel Ghana Music Awards (TGMA) ẹlẹ́karùndínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú Naa Ashorkor Mensah-Doku.[7]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìyàwó àkọ́kọ́ rẹ̀ ni Damilola Adegbite, àmọ́ wọ́n pínyà ní oṣù kẹsàn-án ọdún 2017.[8][9] Ó tún ṣe ìgbéyàwó Bettie Jennifer tó jé oníṣòwò ní Accra, ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹwàá ọdún 2018.[10]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Sylvia (2020)
- The Perfect Picture (2009) bíi Larry
- The Perfect Picture - Lẹ́yìn ọdún mẹ́wàá (2020)[11] bíi Larry Stevens
- An Accidental Zombie (Named Ted) (2018) bíi Ricky
- In line (2017) bíi David
- A Trip to Jamaica (2016) bíi Tayo
- "Happiness is a Four-Letter Word" (2016) bíi Chris
- Flower Girl (2013) bíi Umar Abubakar
- Journey to Self (2012) bíi Dapo
- Single and Married (2012) bíi Jay
- Bad Luck Joe (2018) bíi Joe
- Scorned (2008) bíi Orlando Thompson
- Life and Living It (2007) bíi Ray Austin
- Esohe (2017) bíi Ifagbai
- A Soldier's Story 2; Return from the Dead (2020) bíi Logan
- Love and Cancer (2017)
- Love and War (2013) bíi Daniel
- Moving On (2013) bíi Taye
- Closure Mandate (2022) bíi Dele
- International Affairs (2018) bíi Bode
- Lotanna (2017) bíi Kojo
- The Rangers; Shadows Rising (2016) bíi Garrin
- Sinking Sands (2010) bi Mensah
- One More Day
- The In-laws (2017) bíi Tobi
- Potato Potatho[12] (2017) bíi Gabby
- Kintampo (2018)
- All About Love (2017) bíi Ryan
- Choices (2020)
- Somniphobia (2021) bíi Dokita Brady
- Lovers Discretion (2021) bí Will
- James Town (2016)
- Six hours to Christmas (2010) bíi Reggie
- Swings[13] (2017)
- Sinister Stepsister (2022) - Lifetime Movie Network
- Aborted Assignment (2023) bi Kola
- Finding Odera (2023) bíi Eric
- The American Society of Magical Negroes (2024) bíi Oníṣòwò ti Ìlú Ghana
- I'm Sorry Son (2024) bíi Ray
Orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- A House Divided (UMC) 2019–2020
- Fifty – the series 2020
- BRAT TV 2020
- Tinsel (2008–2013)
- Shuga (season 3) (2013–2015)
Orí ẹ̀rọ-ayélujára
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Our Best Friend's Wedding - Season 1 (2017)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Adeola Adeyemo (18 February 2012). "BN Saturday Celebrity Interview: 'The HOTTEST Nice Guy You’ll Ever Meet!' – Ghanaian TV & Movie Star Chris Attoh of 'Tinsel' reveals ALL exclusively to BN". Bella Naija. Retrieved 18 August 2014.
- ↑ "EXCLUSIVE INTERVIEW: "Love is the one thing we will never comprehend…" CHRIS ATTOH- Ghanaian Actor, TV Host & M-NET’s Tinsel TV Series Star". Archived from the original on 19 August 2014. Retrieved 18 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Women Paint their Dreams on me – Chris Attoh". punchng.com. Archived from the original on 19 August 2014. Retrieved 18 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Ghanaian actor Chris Attoh marries again [Photos"] (in en-US). Citi Newsroom. 2018-10-06. https://citinewsroom.com/2018/10/06/ghanaian-actor-chris-attoh-marries-again-photos/.
- ↑ "Chris, Naa and DJ Black to host VGMA 2016 – Graphic Online". Graphic.com.gh. 2016-05-03. Retrieved 2019-05-14.
- ↑ "Industry Leaders in Business and Entertainment to be Honored at F.A.C.E List Awards". Black Enterprise (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-07-24. Retrieved 2019-05-13.
- ↑ Ghartey, Raphael (2024-06-01). "25th TGMA: Chris Attoh returns as host, co-host with TV3’s Naa Ashorkor for the second time | 3News". 3news.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-06-02.
- ↑ "M.I congratulates Chris Attoh and Damilola Adegbite on engagement". thenet.ng. Archived from the original on 19 September 2014. Retrieved 18 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Exclusive: Chris Attoh opens up to BellaNaija about New Projects, Divorce from Damilola Adegbite & ‘The Kindness Foundation". bellanaija. 25 September 2017. Retrieved 25 September 2017.
- ↑ "Ghanaian actor Chris Attoh marries again [Photos]". Oct 6, 2018. Retrieved May 14, 2019.
- ↑ "Sparrow Production shoots ‘Perfect Picture’ movie again 10 years later". www.ghanaweb.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-09. Retrieved 2021-02-03.
- ↑ "Shirley Frimpong-Manso's 'Potato Potahto' makes it to Netflix – MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-03.
- ↑ "Movie starring Yvonne Nelson, Chris Attoh, Henry Adofo premieres November 25". Entertainment. Nov 22, 2017. Retrieved May 14, 2019.