Tope Tedela
Tọ́pẹ́ Tedela | |
---|---|
Tedela at the 2020 Africa Magic Viewers Choice Awards | |
Ọjọ́ìbí | Temitope Christopher Tedela Ìpínlẹ̀ Èkó |
Ẹ̀kọ́ | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Temitope Christopher Tedela tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Tọ́pẹ́ Tedela jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé ati ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Tọ́pẹ́ gẹ́gẹ́ bí àkọ́bí àwọn òbí rẹ̀ sí ìlú Èkó [4]Àwọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Èkìtì [5] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ girama ti Model College, tí ó wà ní ìlú Mẹran ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè akọ́kọ́ nínú ìmọ̀ Mass Communication ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì Ìpínlẹ̀ Èkó.[6]
Ó ti gba ọ̀pọ̀ amì-ẹ̀yẹ fún àeọn iṣẹ́ takun takun tí ó ń gbé ṣe ní inú agbo àwọn òṣèré Nollyeood. Lára awọn amì-ẹ̀yẹ yí ni: Africa Magic Viewers Choice Award, Nigeria Entertainment Award, Best of Nollywood Award àti Nollywood Movies Award. Wọ́n i wo àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan tí Tades ti gbé jáde ní àwọn sinimá káàkiri ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ ati ní òkè òkun bíi Cannes Film Festival, Toronto International Film Festival àti BFI London Film Festival. Lára àwọn iṣẹ́ rẹ̀ tí ó ti gbé jáde ni: The Lost Okoroshi (2019), What Lies Within (2017), Slow Country (2017), Ojukokoro (2017), Suru L'ere (2016), Out of Luck (2015), A Soldier's Story (2015) àti A Mile from Home tí ó jẹ́ eré tí ó ti fi gba amì-ẹ̀yẹ oríṣiríṣi.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nígbà tí ó kẹ́kọ́ nílé ẹ̀kọ́ fásitì lọ́wọ́, Tọ́pẹ́ kópa lààmì-laaka nínú eré àtìgbà-dégbà onípele tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Edge of Paradise.[7] Ó jáwọ́ nínú ìkópa nínú eré fúngbà díẹ̀ láti lè fojú sínẹ̀kọ́ rẹ̀ , lẹ́yìn tí ó sì kàwé já, ó ṣiṣẹ́ fúgbà díẹ̀ ní ilé iṣẹ́ rédíò ti UNILAG FM.[8] [9] Tọ́pẹ́ fìgbà kan rí ṣe olóòtú ètò lórí ìkanì NTA. Ó ti kópa nínú àwọn eré oríṣiríṣi.[10][11] Ó kópa nínú eré, A Mile from Home.[12] Ní ọdún 2015, Tọ́pẹ́ tún kópa nínú eré A Soldier's Story àti eré Out of Luck. Ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré Suru Le're ní ọdún 2016, gẹ́gẹ́ ẹ̀dá ìtàn Kyle Steven-Adedoyin jẹ́ kí awọn ènìyàn ó fẹ́ láti máa wo eré tí ó bá ti kópa. [13][14] Tọ́pè kópa nínú eré apanilẹ́rín kan tí wọ́n pè Ojúkòkòrò àti Slow Country ní ọdún 2017.[15]Ó tún di gbajú-gbajà olùgbéré-jáde pẹ̀lú eré tìrẹ ty ó gbé jáde tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní What Lies Within.[16]Ní ọdún 2018, kópa nínú eré ọ̀daràn kan tí akọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Knock Out Blessing. Ó tú kópa bí ẹ̀dá-ìtàn Dr. Dauda nínú eré The Lost of Okoroshi[17] Tedela tún kópa nínú eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ The Ghost and the House of Truth. [18]
Àwọn iṣẹ́ mìíràn tí ó tún ń ṣe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2016, wọ́n fi Tọ́pẹ́ Tedela ṣe aṣojú fún ilé-iṣẹ́ Global Rights, ilé-iṣẹ́ tí ó ń rí sí ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn láti lè jẹ́ kí ó lè ṣe ìpolongo tako ìwà ìfipábánolòpọ̀ awọn ọmọ obìnrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [19]
Àwọn amì-ẹ̀yẹ àti ìfisọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Amì-ẹ̀yẹ | Ìsọ́rí | Iṣẹ́ | Èsì |
---|---|---|---|---|
2017 | Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Supporting Role | Slow Country | Yàán |
2016 | City People Entertainment Awards | Best Actor in a Supporting Role | Suru L'ere | Yàán |
Nigeria Entertainment Awards | Best Actor in Supporting Role | Yàán | ||
2014 | 10th Africa Movie Academy Awards | Most Promising Actor | A Mile from Home | Yàán |
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor In A Drama | Gbàá | ||
2014 Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Leading Role (English)[20] | Gbàá | ||
Revelation of the Year (Male) | Yàán | |||
2014 Golden Icons Academy Movie Awards | Most Promising Actor | Gbàá | ||
Best On-Screen Duo | Yàán | |||
2014 Nigeria Entertainment Awards | Best Actor in a Lead Role | Gbàá | ||
2014 Nollywood Movies Awards | Best Actor in a Leading Role (English) | Yàán | ||
Best Rising Star (Male) | Gbàá | |||
2014 Express Star Awards[21] | Rising Star | Himself | Gbàá |
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2007 | Twisted | Sola | |
2013 | Awakening | ||
2013 | Torn | Young Olumide | |
2013 | A Mile from Home | Lala/Jude Odaro | |
2013 | Cyanide | Emeka | Short Film |
2014 | Another Day to Die Young | Comrade | TV Film |
2014 | Birthday Bash | Scoda | |
2014 | Leeway | Chuks | Short Film |
2015 | Lunch Time Heroes | Deji | with Omoni Oboli & Dakore Akande |
2015 | Apostates | Osas | |
2015 | A Soldier's Story | Major Egan | |
2015 | Out of Luck | Dayo | |
2016 | Suru L'ere | Kyle Stevens Adedoyin | with Rita Dominic |
Ojukokoro (Greed)[22][23] | Sunday | ||
2017 | King Invincible | Taari | with Gabriel Afolayan |
Slow Country | Osas | with Majid Michel | |
What Lies Within[24] | Gboyega | Also Producer | |
2018 | Knock Out Blessing | Yomi | |
2019 | The Lost Okoroshi | Dr Dauda | |
2019 | The Ghost and the House of Truth | Barrister Tokunbo |
Àwọn eré orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkòrí | Ipa tí ó kó | Àríwísí |
---|---|---|---|
2006 | Edge of Paradise | Julian | |
2008 | My Mum & I | June | |
2008 | Super Story (Omojuwa) | Tesiro | |
2012 | Burning Point | ||
2012 | Tweeters | Kunle | |
2013 | Super Story (The Secret) | Tai | |
2014 | Oasis [25] | Oreva | |
2015 | The Team (TV series) | Efe | |
2016 | Jamestown | Lucky | |
2017 | Jemeji | Obi | Chief |
2019 | Powder Dry | Arthur | |
2019 | Underbelly | Nonso |
Eré orí-ìtàgé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkòrí | Ipa tí ó kó | Notes |
---|---|---|---|
2011 | Man Talk, Woman Talk | Emeka | |
2014 | Diagnosis | Emeka | |
2014 | The Agency | Fawaz | |
2019 | The Mistress of Wholesome | Nengak Josiah | |
2019 | The Wives | Lawyer | |
2019 | Whumanizer | Tunde Bridges |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://dailytimes.ng/tope-tedela-produces-first-movie/
- ↑ "Tope Tedela profile at". imdb.com. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ "Tope Tedela denies not receiving Payments". premuimtimes.com. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ Abimboye, Michael. "EXCLUSIVE: Tope Tedela Squashes Rumour of Not Being Paid for Award-winning Role". Archived from the original on 2014-07-25. https://web.archive.org/web/20140725122429/http://connectnigeria.com/articles/2014/03/14/exclusive-tope-tedela-squashes-rumour-of-not-being-paid-for-award-winning-role/.
- ↑ "Tope Tedela nominated for AMAA Awards". news247.com.ng. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ Okeugo, Peter (2014-06-23). "My parents almost dumped me in remand home – Tope Tedela". Archived from the original on July 13, 2014. https://web.archive.org/web/20140713112025/http://www.punchng.com/spice/entertainment-spice/my-parents-almost-dumped-me-in-remand-home-tope-tedela/.
- ↑ Agbanusi, Nneka. ""Hollywood Should Expect Me Soon" – Tope Tedela". happenings9ja.com. Archived from the original on October 26, 2014. Retrieved 26 October 2014.
- ↑ Obioha, Vanessa (6 July 2014). "A Good Headstart". This Day. Archived from the original on July 7, 2014. https://web.archive.org/web/20140707204653/http://www.thisdaylive.com/articles/a-good-headstart/182833/.
- ↑ "Tope Tedela Interview on Jara". africamagic.dstv.com. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ "Tope Tedela interview on YNaija". ynaija.com. Archived from the original on April 28, 2014. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ "Tope Tedela not paid for award-winning role". thenet.ng. Retrieved 23 April 2014.
- ↑ Abodunrin, Akintayo. "South African, Ghanaian Films Set To Shine At AMAA 2014". Nigerian Tribune. http://www.tribune.com.ng/arts-culture/item/2755-south-african-ghanaian-films-set-to-shine-at-amaa-2014/2755-south-african-ghanaian-films-set-to-shine-at-amaa-2014.
- ↑ "Movie Review: 'Suru L’ere' – A Story Left Untold! – Online Entertainment and Lifestyle Magazine in Nigeria" (in en-US). Online Entertainment and Lifestyle Magazine in Nigeria. 2016-02-19. Archived from the original on December 1, 2017. https://web.archive.org/web/20171201131657/https://happenings.com.ng/movie-review-suru-lere-a-story-left-untold/.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Tope Tedela: Actor is "Kyle Stevens Adedoyin" in upcoming movie "Surulere"" (in en-US). Archived from the original on 2017-06-03. https://web.archive.org/web/20170603062249/http://www.pulse.ng/movies/tope-tedela-actor-is-kyle-stevens-adedoyin-in-upcoming-movie-surulere-id3922517.html.
- ↑ "Majid Michel, Ivie Okujaye Egboh, Tope Tedela & More star in Eric Aghimien’s "Slow Country" | Watch the Trailer on BN TV – BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-22.
- ↑ Izuzu, Chidumga. "Tope Tedela: Actor produces 1st movie "What Lies Within"" (in en-US). Archived from the original on 2017-08-21. https://web.archive.org/web/20170821215609/http://www.pulse.ng/movies/tope-tedela-actor-produces-1st-movie-what-lies-within-id5074520.html.
- ↑ https://www.hollywoodreporter.com/review/lost-okoroshi-1240868
- ↑ https://ynaija.com/the-quiet-devastating-power-of-akin-omotosos-the-ghost-and-the-house-of-truth/
- ↑ https://www.bellanaija.com/2016/09/ego-boyo-aramide-tope-tedela-bose-oshin-and-more-celebrities-team-up-with-global-rights-to-end-sexual-violence/
- ↑ Izuzu, Chidumga. "BON Awards 2014: Tope Tedela, Ivie Okujaye, 'Silence' Win Big". pulse.ng. Archived from the original on 5 April 2017. Retrieved 26 October 2014.
- ↑ Dede, Steve. "Express Star Awards excites Tope Tedela as he picks Nollywood's Rising Star Trophy on July 27". http://showbizplusng.blogspot.com/. Retrieved 12 August 2014. External link in
|website=
(help) - ↑ https://www.youtube.com/watch?v=HZ6ItZNKQO0
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-06-15. Retrieved 2020-11-18.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-08-21. Retrieved 2020-11-18.
- ↑ "Attend The Premiere Of OASIS TV Series With Monalisa Chinda, Moet Abebe, Beverly Naya & Others". DaDeliverer. Gist Around. Archived from the original on March 6, 2016. Retrieved 1 November 2014.
Ìtàkùn Ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- CS1 errors: external links
- Nigerian male film actors
- University of Lagos alumni
- Male actors from Lagos
- Yoruba male actors
- Year of birth missing (living people)
- Àwọn ènìyàn alààyè
- 21st-century Nigerian male actors
- Nigerian radio personalities
- Yoruba radio personalities