Jump to content

Nancy Isime

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nancy Isime
Nancy Isime at the AMVCAs 2020
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kejìlá 1991 (1991-12-17) (ọmọ ọdún 33)
Edo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́2011- till date

Nancy Isime (tí wọ́n bí ní ọjọ́ 17 oṣù December, ọdún 1991) jẹ́ òṣèrébìnrin àti oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ-ayélujára tí orílẹ̀-èdè Naijiria[1] .

Early life and background

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìpínlẹ̀ Ẹdó, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́ bí Nancy Isime sí, sínú ẹbí tó wá láti ìran Esan.[2] Lẹ́yìn tó parí ẹ̀kọ́ girama ní Benin City, ó lọ sí University of Lagos, láti lọ gboyè ẹ̀kọ́ si[3].

Nancy Isime pàdánú ìyá rẹ̀ ní ìgbà tó wà ní ọmọ ọdún márùn-ún, bàbá rẹ̀ ló sì tọ́ ọ dàgbà.[4] Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó, níbi tó ti ka ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ girama. Kò parí ẹ̀kọ́ girama rẹ̀ ní Èkó, Benin City ni ó ti parí ẹ̀kọ́ girama rè. Ó kẹ́kọ̀ọ́ olóṣù mẹ́fà ní University of Port Harcourt, kí ó tó wá lọ sí University of Lagos, láti gba oyè diploma nínú ẹ̀kọ́ Social Works[5].

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • The Set Up 2 (2022)
  • Obara'm (2022)
  • Shanty Town (2023)
  • Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Fíìmù Èsì Ìtọ́ka
    2016 City People Entertainment Awards Best VJ of the Year N/A Gbàá [6]
    Nigerian Broadcasters Merit Awards Sexiest On Air Personality (female) Hip TV Gbàá [7]
    2017 The Future Awards Best On Air Personality (Visual) N/A Gbàá [8][9]
    2018 2018 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Lead Role - English Disguise Wọ́n pèé [10]
    City People Movie Awards Most Promising Actress (English) N/A Gbàá [11]
    2019 Best Supporting Actress (English) N/A Gbàá [12]
    Best of Nollywood Awards Best Kiss in a Movie Jofran Gbàá [13]
    Best Actress in a Lead role –English Wọ́n pèé [14]
    2021 Net Honours Most Popular Media Personality (female) N/A Wọ́n pèé [15]
    Most Searched Media Personality N/A Wọ́n pèé
    2022 2022 Africa Magic Viewers' Choice Awards|Africa Magic Viewers' Choice Awards Best Actress in A Comedy Kambili: The Whole 30 Yards Wọ́n pèé [16]
    Best Actress in A Drama Superstar Wọ́n pèé

    Iṣẹ́ tóyàn láàyò

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

    Nancy Isime bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré láti inú fíìmù orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán kan tí àkọ́lé rè ń jẹ́ Echoes, ní ọdún 2011. Ó sì tún jẹ́ olóòtú ètò kan lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, tí wọ́n pè ní The Squeeze, What's Hot, àti MTN Project Fame apá keje[17]. Ní ọdún 2016, ó rọ́pò Toke Makinwa láti ṣe olóòtú ètò kan tí wọ́n pè ní Trending lórí HipTV.[18][19] Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò ti ètò The Headies award pẹ̀lú Reminisce.[20] Òun náà ni olóòtú ètò The Voice Nigeria tó wáyé ní ọdún 2021.[21] Ní ọdún 2019, Isime ṣàgbéjáde ètò tirẹ̀, tó pè ní The Nancy Isime Show.[22] Ní ọdún 2020, ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùgbàlejò ti ètò The Headies award pẹ̀lú Bovi.[23] Ní ọdún 2022, ó kópa nínú fíìmù Netflix kan, tí àkọ́lé rè jẹ́ Blood Sisters, ẹ̀dá-ìtàn tó sì ṣe ni Kemi. Ilé-iṣẹ́ Mo Abudu tí wọ́n ń pè ní Ebonylife TV studio ló ṣàgbéjáde eré yìí. Ní ọdún 2023, ó kópa nínú eré Shanty Town, gẹ́gẹ́ bí i ẹ̀dá-ìtàn Shalewa[24].

    Àwọn ìtọ́kasí

    [àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
    1. "TV Personality, Actress & also a Model? "On The Real" Star Nancy Isime is a Triple Threat". bellanaija.com. Retrieved 6 February 2017. 
    2. "I have no problem baring my cleavage - Nancy Isime". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-05. Retrieved 2022-08-27. 
    3. "To become superstars, ladies need talent, not 'connection'- Model - Vanguard News". vanguardngr.com. 4 August 2016. Retrieved 6 February 2017. 
    4. Oyedele, Oluwamuyiwa (2021-02-24). "How I lost My Mum At 5 - Nancy Isime". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-27. 
    5. "I have no problem baring my cleavage - Nancy Isime". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 5 March 2017. Retrieved 25 April 2021. 
    6. "Full List Of Winners at 2016 City People Entertainment Awards - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". thenet.ng. 26 July 2016. Archived from the original on 8 December 2016. Retrieved 6 February 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
    7. Popoola, Kazeeem. "Finally! Here Is Authentic List Of Nominees For NBMA 2015". Nigeria Voice. 
    8. "2017 Future Awards Africa winners". Punch. 
    9. "Wizkid, Davido, Joshua winners at Africa’s Future Awards". Vanguard. Retrieved 25 October 2020. 
    10. "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 December 2018. Retrieved 23 December 2021. 
    11. "Nominees For 2018 City People Movie Awards". City People. 
    12. "Winner Emerge @ 2019 City People Movie Awards". 14 October 2019. Retrieved 20 October 2020. 
    13. "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition in Kano". Pulse. 
    14. Bada, Gbenga (15 December 2019). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 October 2021.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
    15. "Net Honours - The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 December 2021. 
    16. "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list". BBC News Pidgin. https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021. 
    17. "I can't date a man who is broke". The Nation. http://thenationonlineng.net/cant-date-man-broke/. Retrieved 13 October 2016. 
    18. "Nancy Isime, Where Have You Been Hiding?". TNS. 25 June 2016. Archived from the original on 13 October 2016. Retrieved 13 October 2016. 
    19. "Hip Tv unveils Toke Makinwa's replacement for 'Trending'". Nigerian Entertainment Today. 31 July 2015. Retrieved 6 February 2017. 
    20. "Headies 2019: Teni, Falz, Burna Boy win big at 13th edition". Pulse.ng. 19 October 2019. Archived from the original on 19 October 2019. https://web.archive.org/web/20191019214707/https://www.pulse.ng/entertainment/music/headies-2019-all-the-winners-at-the-13th-edition/cvevtzt. 
    21. "Premiere: Nancy Isime, Toke Makinwa graced The Voice Nigeria Season 3 with glitz and glam". Vanguard. 30 March 2021. Retrieved 16 June 2022. 
    22. "TV personality, Nancy Isime launches TV Show". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 October 2019. Retrieved 30 March 2022. 
    23. Meet the Hosts for the #14thHeadies, Nancy Isime & Bovi
    24. BellaNaija.com (2022-12-28). "Meet the Cast of “Shanty Town,” the Nigerian Crime Thriller Coming to Netflix in January". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-06.