Toke Makinwa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Toke Makinwa
Ọjọ́ìbí3 Oṣù Kọkànlá 1984 (1984-11-03) (ọmọ ọdún 39)[1]
Lagos, Nigeria
Ẹ̀kọ́Federal Government Girls' College and University of Lagos
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati onkọwe
Olólùfẹ́
Maje Ayida (m. 2014–2017)
[2][3]
WebsiteOfficial website

Toke Makinwa (bii ni ọjọ kẹta oṣu ọkanla ọdun 1984) je omo orile ede Naijiria. O je agbóhùnsáfẹ́fẹ́, ati onkọwe.[4][5][6][7][8] O kọ iwe On Becoming ni odun 2016 ni osu mọkanla. O je adari eto ọkọ owurọ ni ori 93.7 FM.[9][10]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọn bí Toke Mali wá ní ọjọ́ kẹta oṣù kọkànlá ọdún 1984 sì ìlú Èko ni Ipinle Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girls College ní ìlú Oyo, Ibadan Makinwa lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos ni ibi tí ó ti kà English and Literature.

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2010, Makinwa kọ́kọ́ fi ara rẹ hàn ní orí ẹ̀rọ agbohun sì afẹ́fẹ́ tí Rythm 93.7 Fm ni ori eto ọkọ ÒWÚRỌ̀.[11] Ní ọdún 2012, ó ṣe atọkun ètò Obìnrin tí ó rẹwà jùlo ni ìpínlè Nàìjíríà.[12][13] Óun pelu Tosyn Bucknor àti Oreka Godis jọ ṣe atọkun fún ètò Flytime TV's Live Chicks.[14] Ni ọdún 2012 yí náà ni ò béèrè eto Toke Moments ní orí YouTube vlog.[15][16] Ní ọdún 2014, Hip Hop World Wide Magazine kéde Makinwa gẹ́gẹ́ bí atọkun ètò Ifọrọwanilẹnuwo àti ọ̀rọ̀ ile ise won.[17][18] Ó gbà ìṣe gẹ́gẹ́bí ìkàn lára àwọn atọkun ètò ni ilu ìṣe Ebony Tv fún ètò Moments.[19]

Makinwa tí se atọkun ètò fun ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò bíi Future and City People Award ni odun 2013 àti Headies Award ni ọdún 2014.[20][21] Makinwa kọ ìwé On Becoming ni osu kọkànlá ọdún 2016. Ìwé na sọ̀rọ̀ nípa ìsòro tí ó ní àti tí ọkọ rẹ ṣe já kú ń lẹ̀.[22][23][24] Makinwa lọ ká kiri àwọn ìlú bí South Afrika, U.S.A, U.K àti àwọn ìlú miiran ni ilẹ̀ Áfíríkà láti tá ìwé náà.[25][26][27][28] Ní ọdún 2017, ó tún kọ ìwé miiran tí ó pè àkòrí rẹ ni Handbag line.[29][30][31]

Ní ọdún 2013, Makinwa jẹ́ asojú fún ilé ìṣẹ́ United Africa Company Of Nigeria, òun pelu Osas Ighodaro, Dare Art Alade, àti Dan Foster.[32]

Toke Makinwa

Ilé ìṣẹ́ olówó iyebíye tí Nestle ni Ipinle Nàìjíríà fi ṣe ojú ọjà Maggi.[33]Ní odùn 2016, ó di asoju fún ilé ìṣẹ́ Mecran Cosmetics.[34] Òun sì ní asojú fún ilé ìṣẹ́ Payporte[35] àti Ciroc.[36]

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Makinwa se ìgbéyàwó pẹlu Maje Ayida ní ọjọ́ Kàrún dínlógún oṣù kìíní ọdún 2014, olólùfẹ́ rẹ fún ọdún mẹjọ.[37] Ní ọdún 2015, ó pínyà pelu Ayida lẹ́yìn tí ó rí wípé ó ti fún ẹlòmíràn lóyún.[38][39][40] Ní ọjọ́ Kàrún osù Kẹ̀wá ni ilé ẹjọ́ tún ìgbéyàwó náà kà ni ìpínlè èkó lórí pé Ayida ṣe àgbèrè.[41][42]


Ẹ̀bùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award Category Result Notes
2012 The Future Awards [43][44] On Air Personality of the Year (Radio) Yàán [45]
2013 Nigeria Broadcasters Awards [46] Outstanding Female Presenter of the Year Gbàá
2013 Nigeria Entertainment Awards Radio OAP of the Year Wọ́n pèé
2014 Nickelodeon Kids' Choice Awards [47] Favourite Nigerian On Air Personality Yàán [48]
2014 Nigeria Entertainment Awards Entertainment Personality of the Year Wọ́n pèé
Best OAP of the Year Wọ́n pèé
2014 ELOY Awards[49] TV Presenter of the Year & Brand Ambassador (Maggi) Wọ́n pèé N/A
2017 Glitz Awards[50] Style Influencer of the Year Gbàá
2017 Avance Media[51] Most Influential Young Nigerian in Media Gbàá
2018 Africa Youth Award[52] 100 Most Influential Young Africans[53] Gbàá

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Happy Birthday to OAP; Toke Makinwa". Daily Times of Nigeria. 3 November 2014. Retrieved 4 November 2014. 
  2. "Photos: Toke Makinwa & Maje Ayida’s Official Wedding Pictures". lailasblog.com. 21 January 2014. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 8 October 2017. 
  3. "Court finally dissolves Toke Makinwa’s marriage". lailasblog.com. 6 October 2017. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 6 October 2017. 
  4. "Watch Toke Makinwa's Vlog of the week". bellanaija.com. 18 June 2014. Retrieved 17 July 2014. 
  5. "My relationship with Maje Ayida over- Toke Makinwa". punchng.com. Archived from the original on 2 June 2014. Retrieved 2 June 2014. 
  6. "My Wedding Idea came when I was 5". punchng.com. Archived from the original on 5 June 2014. Retrieved 2 June 2014. 
  7. "Toke Makinwa wins Best OAP of the year". Retrieved 2 June 2014. 
  8. "Toke Makinwa launches skincare product 'Glow by TM'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-13. Retrieved 2019-03-31. 
  9. Mix, Pulse. "Toke Makinwa's Vlog: Toke Moments : Marriage & the Unnecessary Pressure from Society". pulse.ng. Retrieved 30 May 2016. 
  10. "Read Toke Makinwa’s ‘On Becoming’ book: Why Maje didn’t get her pregnant, begged her for money & more". lailasblog.com. 28 November 2016. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 8 October 2017. 
  11. "'You are totally fake' - Toke Makinwa's Rhythm FM co-host lashes out » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-22. Retrieved 2019-03-31. 
  12. "Toke Makinwa", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2019-03-27, retrieved 2019-03-31 
  13. "Toke Makinwa and Chris Okenwa to host MGBN 2012". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-05-01. Retrieved 2019-03-31. 
  14. Says, Weapon (2013-03-04). "Toke Makinwa explains her absence on 3 Live Chicks". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31. 
  15. "It is laughable to say I have a child –Toke Makinwa". Punch Newspapers. 
  16. MGA1 (2019-02-01). "Watch A New Episode Of Toke Makinwa‘s ‘Toke Moments’". MediaGuide.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-03-27. Retrieved 2019-03-31. 
  17. Hip TV (2014-11-05), TRENDING HOST TOKE MAKINWA GETS SPECIAL BIRTHDAY TREAT (Nigerian Entertainment News), retrieved 2019-03-31 
  18. BellaNaija.com (2014-01-10). "Toke Makinwa to Host New Show “Trending” on Hip TV | To Debut this January". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31. 
  19. "Toke Makinwa To Get Her Own TV Show". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-01-10. Retrieved 2019-03-31. 
  20. BellaNaija.com (2013-12-20). "Toke Makinwa & Vector to Host the 2013 Future Awards Tonight in Port Harcourt". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31. 
  21. BellaNaija.com (2014-09-18). "Bovi & Toke Makinwa are the Hosts of the 2014 Headies!". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-03-31. 
  22. "How gas cylinder explosion killed Toke Makinwa's parents". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-11-29. Retrieved 2019-04-01. 
  23. "Read 10 Shocking Revelations From Toke Makinwa's Book, 'On Becoming' | Nigerian Celebrity News + Latest Entertainment News". stargist.com. Retrieved 2019-04-01. 
  24. Augoye, Jayne (2017-10-06). "Toke Makinwa, Maje Ayida finalise divorce". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01. 
  25. MediaGuide (2016-11-29). "Just One Day After Launch, Toke Makinwa Becomes Amazon's Best Selling Author". MediaGuide.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-15. Retrieved 2019-04-01. 
  26. BellaNaija.com (2016-12-20). "Toke Makinwa’s “On Becoming” Book Launch in Abuja was so Emotional! See all the Photos on BN". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01. 
  27. "Toke Makinwa Takes Her Book Tour To Kenya Despite Her Estranged Husband's Threat To Sue - Gistmania". www.gistmania.com. 2017-02-09. Retrieved 2019-04-01. 
  28. KOKO (2017-06-27). "Photos From Toke Makinwa's 'On Becoming' South Africa Book Tour". KOKO TV Nigeria | Nigeria News & Breaking Naija News. Retrieved 2019-04-01. 
  29. BellaNaija.com (2017-11-03). "EXCLUSIVE: #BabyGirlForLife! Toke Makinwa launches Luxury Bag Line". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01. 
  30. "Laura Ikeji Set To Buy Toke Makinwa’s Bag". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-29. Retrieved 2019-04-01. 
  31. "Toke Makinwa launches skincare product 'Glow by TM'". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-13. Retrieved 2019-04-01. 
  32. "Toke, Foster & Osas becomes Lipton ambassandors". bellanaija.com. 17 June 2013. Retrieved 7 June 2014. 
  33. "Tiwa savage , Toke Makinwa bag mouth watering deals!". Vanguard News. 11 April 2014. 
  34. "TOKE MAKINWA IS THE NEW BRAND AMBASSADOR FOR MECRAN COSMETICS…GET THE SCOOP!". Archived from the original on 10 June 2016. Retrieved 30 May 2016. 
  35. "Tayo Faniran, Toke Makinwa unveiled as Payporte ambassadors". Vanguard News. 29 January 2015. 
  36. "Toke Makinwa becomes the first female ambassador for Ciroc in Nigeria". Olori Supergal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-27. Retrieved 2019-04-01. 
  37. "Toke and Maje surprise wedding ceremony". bellanaija.com. Retrieved 7 June 2014. 
  38. "I’ll quit if I’m unhappy in next marriage - Toke Makinwa". Vanguard News. 8 August 2019. 
  39. "Rhthymn 93.7 OAP, Toke Makinwa and Maje Ayida cancel engagement". 27 August 2012. 
  40. "Toke Makinwa’s Husband, Maje Makes First Public Appearance ‘ALONE’ Weeks After Marriage Crisis - INFORMATION NIGERIA". INFORMATION NIGERIA. Retrieved 30 May 2016. 
  41. Augoye, Jayne (6 October 2017). "Toke Makinwa, Maje Ayida finalise divorce - Premium Times Nigeria". 
  42. "Court finally dissolves Toke Makinwa’s marriage". lailasblog.com. Archived from the original on 8 October 2017. Retrieved 6 October 2017. 
  43. "Toke Makinwa nominated for Future Awards". Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 June 2014. 
  44. Damilare Aiki (18 July 2012). "Future Awards nominees unveiled". bellanaija.com. Retrieved 6 June 2014. 
  45. "2012 Future Awards Winners". jaguda.com. Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 June 2014. 
  46. "Nigeria Broadcasters Awards list of winners". bellanaija.com. 12 December 2013. Retrieved 6 June 2014. 
  47. "Nickelodeon Kids Choice Awards nominees". bellanaija.com. 25 February 2014. Retrieved 6 June 2014. 
  48. "Toke Makinwa, Toolz and others for Nicklelodeon Kids Choice Awards". informationng.com. 26 February 2014. Retrieved 6 June 2014. 
  49. "Exquisite Lady of the Year (ELOY) Awards Seyi Shay, Toke Makinwa, Mo’Cheddah, DJ Cuppy, Others Nominated". Pulse Nigeria. Chinedu Adiele. Retrieved 20 October 2014. 
  50. BellaNaija.com (2017-08-20). "Toke Makinwa wins Style Influencer of the Year at Glitz Style Awards 2017". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01. 
  51. pakpah. "Toke Makinwa voted 2017 Most Influential Young Nigerian in Media" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-01. 
  52. Amodeni, Adunni (2018-09-07). "Falz, Davido, Ahmed Musa listed among 100 most influential young Africans". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-04-01. Retrieved 2019-04-01. 
  53. "Davido, Toke Makinwa. Mohammed Salah, Falz named on 100 most influential young Africans list". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-06. Retrieved 2019-04-01.