Bovi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Bovi Ugboma
Bovi at the Africa Magic Viewers Choice Awards in July 2014.
Orúkọ àbísọAbovi Ugboma
Ìbí(1979-09-25)Oṣù Kẹ̀sán 25, 1979
Benin City, Edo, Nigeria
GenresActing, comedy
SpouseKris Asimonye Ugboma
Ibiìtakùnbovitv.com

Bovi jẹ́ aláwàdà, òṣèré, àti ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,[1] Ó ti gbé ètò Man on Fire kan tó gbajúmọ̀ jákè-jádò agbáyé.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bovi Ugbona ni wọ́n bí nu ìlú Bìní tí ó jẹ́ olú Ìlú fún Ìpínlẹ̀ Ẹdó, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti UNIBEN ní ọdún 1991, ó tún wọlé sílé-ẹ̀kọ́ ti Ìjọba àpapọ̀ í Ìlú Ugheli ní Ìpínlẹ̀ Delta, àwọn òbí rẹ̀ mu kúrò ní ilé-ẹ̀kọ́ yí lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Edokpolor ní ìlú Bìní tí wọn ń gbé kí wọ́n lè baà mójú to. Àmọ́ ẹ̀kọ kó ṣojú mímu fun ni wọ́n bá tún muọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Onicha-_Olona. Lẹ́yìn tí ó parí ilé-ẹ̀kọ́ náà, ó wọn ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ní ọdún 1998 ní Ìpínlẹ̀ Delta níbi tí ó ti kẹ́kòọ́ nípa eré-oníṣẹ.[3]

Iṣẹ́.rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aláwàdà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bérẹ̀ iṣẹ́ àwàdà ṣíse ní inú oṣù Kẹrin ọdún 2007,[4] níbi tí ó ti kọ́kọ́ fara hàn nínú eré Extended Family,[5] tí ó jẹ́ wípé òun náà ni ó kọọ́ tí ó darí rẹ̀ tí ó sì gbe jáde. [6] eré náà gbajúmọ̀ gidi, nígbà tí yóò fi di ọdún 2008, Bovi ti ń kópa nínú àwọn ètò ọlọ́kan-ò-jọkan káàkiri ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[7] Ó di gbajú-gbajà látàrí ipa rẹ̀.nínú ètò Nite of 1000 Laughs tí ọ̀gbẹ́ni Opa Williams gbé kalẹ̀ ní ọdún 2013. Nínú ètò kan tí òun náà gbé kalẹ̀ tí ó pè ní Bovi- Man on Fire ní ọdún 2014, ni ó ti ṣe àfihàn àwọn òṣèré olórin jànkàn-jànkàn bí Jarule àti Ashanti hàn. Ètò yí ti fún Bovi ní ànfaní láti ṣe ìrìn-àjò lọ sí àwọn orílẹ̀-èdè bíi Amẹ́ríkà, London, Melbourn àti Toronto ní ọdún 2017. Lẹ́yìn tí ó padà dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2019, ó bẹ̀rẹ̀ ètò míràn tí ó pè ní "BACK TO SCHOOL Bovi ti ní ìbáṣepọ̀ tó Yanrantí pẹ̀lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ ní inú iṣẹ́ àwàdà bí : I Go Dye, I Go Save, Basketmouth, Buchi, Odogwu, Okey Bakassi, Julius Agwu àti bẹ̀ẹ́ bẹ̀ẹ́ lọ.[8]

Àwọn eré tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bovi kọ́kọ́ gbé eré rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde tí ó pè ní It's Her Day ní ọjọ́ Kẹsàán oṣù kẹsàán ọdún 2016.[9]Wọ́n yàn án fún amì-ẹ̀yẹ AMVCA gẹ́gẹ́ bí aláwàdà tó oeregedé jùlọ. Wọ́n tún yàn án fún amì-ẹ̀yẹ yí fún ìgbà kẹta fún iṣẹ́ tí ó yàn láàyò.[10]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. SilverbirdsTV (February 17, 2014). "Comedy: Bovi says he's not an overnight success". SilverbirdsTV. Archived from the original on February 26, 2014. Retrieved 2014-02-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. View Nigeria (July 8, 2014). "Bovi Tells Us A Secret + A Revealing Birthday Message For Richard Mofe Damijo". View Nigeria. Archived from the original on October 3, 2017. Retrieved 2014-09-23.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Daily Times NG (March 10, 2013). "Comedian Bovi Ugboma Stages 'Man on Fire' tonight". Daily Times NG. Archived from the original on April 19, 2013. Retrieved March 10, 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. nationaldailyng (February 14, 2012). "BIG BOY BOVI". nationaldailyng. Archived from the original on September 25, 2013. Retrieved February 14, 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. dailyindependentnig (March 13, 2013). "I am my biggest competition – Bovi". dailyindependentnig. Archived from the original on March 12, 2013. Retrieved March 13, 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. Modern Ghana (February 10, 2014). "Bovi Ugboma Denies Saying He Is Richer Than Celebrities Who Are Endorsed". Modern Ghana. Retrieved 2014-02-10. 
  7. Modern Ghana (March 12, 2013). "The Bovi Ugboma Show". Modern Ghana. Archived from the original on February 26, 2014. Retrieved March 12, 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Punchng (March 31, 2013). "I would have been a footballer –Bovi". Punchng. Archived from the original on March 31, 2013. Retrieved March 31, 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. Editor, Online (2016-10-07). "Bovi’s Movie Premiere "It’s Her Day"" (in en-US). THISDAYLIVE. https://www.thisdaylive.com/index.php/2016/10/08/bovis-movie-premiere-its-her-day/. 
  10. "76’, 93 days, top AMVCA nominations (Full nominee list)" (in en-US). Punch Newspapers. http://punchng.com/76-93-days-top-amvca-nominations/. 

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]