Anne Njemanze
Anne Njemanze | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Anne Njemanze Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Nollywood Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Olólùfẹ́ | Segun Arinze Silver Ojieson |
Àwọn ọmọ | Renny Morenike Njemanze |
Anne Njemanze, jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó gbajúmọ̀ jùlọ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu àwọn eré bíi Domitila, Tinsel, Ìrètí àti Colourless.[2][3]
Ọ̀rọ̀ Ayé Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú òṣèré Nollywood Segun Arinze, ṣùgbọ́n àwọn méjèjì ti pínyà.[4] Wọ́n bí ọmọbìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ n ṣe Renny Morẹ́nikẹ́.[5][6]
Ní Oṣù Kọkànlá Ọdún 2013, ó tún ṣe ìgbeyàwó pẹ̀lú Silver Ojieson, ṣùgbọ́n ìgbeyàwọ́ náà kò tún ju oṣù mẹ́jọ lọ tí wọ́n fi kọrawọnsílẹ̀.[7]
Iṣẹ́ Ìṣe Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 1995, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ pẹ̀lú kíkópa nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Rattle Snake. Lẹ́hìn náà ló di ìlúmọ̀ọ́ká pẹ̀lú kíkópa rẹ̀ nínu eré tẹlifíṣọ̀nù Domitilla àti Domitilla II.[8] Lẹ́hìn náà, Ó tún kópa nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ True Confession ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Liz Benson.
Ní ọdún 2012, ó kó ipa ti "Inspector Sankey" nínu eré M-Net aláṣeyọrí kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Tinsel .[9]
Àwọn Eré Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Genre | Ref. |
---|---|---|---|---|
1995 | Rattle Snake | Herself | Home Video | [10] |
Rattle Snake 2 | Herself | Home Video | ||
1996 | Domitila | Domitilla | Home Video | |
Domitilla II | Domitilla | Home Video | ||
1997 | True Confession | Home Video | ||
2004 | Living Abroad | Herself | Home Video | |
Best Lovers | Home Video | |||
2012 | Tinsel | Inspector Sankey | Home Video | |
2015 | Hope | Ireti | Short film | |
2016 | Ìrètí | Ireti | Short film | |
Colourless | Mrs. Okai | Film | ||
2018 | The Lost Café | Ose's Mother | Film |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Actress, Anne Njemanze Steps out with Sneakers on Native Attire". modernghana. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Anne Njemanze sị na ọ ga-amasị ya ịlụ di nke ugboro atọ ma mụọ nwa ọzọ". BBC. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Anne Njemanze: Films". MUBI. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Nollywood actress, Anne Njemanze celebrates her daughter who turns a year older today". bioreports. Retrieved 13 October 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Nollywood actress, Anne Njemanze celebrates her daughter who turns a year older today". lindaikejisblog. Retrieved 13 October 2020.
- ↑ "Segun Arinze’s Daughter Renny, Accuses him of Sending her ‘fake’ Happy Birthday Wishes on Instagram". motherhoodinstyle. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Segun Arinze’s Former Wife, Anne Njemanze Leaves Second Marriage Due To Domestic Abuse". motherhoodinstyle. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Sequel of 1996 Nollywood classic, Domitilla, ‘in the works’". premiumtimesng. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "'Domitilla' star's marriage crumbles after 8-months!". pulse. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Five Classic Nigerian Stories Coming To Cinemas". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-07-05. Archived from the original on 2021-05-09. Retrieved 2021-05-24.
Ìjápọ Síta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from June 2024
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Webarchive template wayback links
- Year of birth missing (living people)
- Nigerian television actresses
- 20th-century Nigerian actresses
- Nigerian film actresses
- 21st-century Nigerian actresses
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn òṣeré ará Nàìjíríà
- Ọdún ọjọ́ìbí kòsí (àwọn ènìyàn alààyè)