Funmilola Aofiyebi-Raimi
Ìrísí
Funlola Aofiyebi-Raimi | |
---|---|
Aofiyebi-Raimi in 2010 | |
Ọjọ́ìbí | Abibat Oluwafunmilola Aofiyebi |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | FAR |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996 Àdàkọ:En dash present |
Gbajúmọ̀ fún | Tinsel |
Olólùfẹ́ | Olayinka Raimi |
Funlola Aofiyebi-Raimi Listen tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Abibat Oluwafunmilola Aofiyebi tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí FAR, jẹ́ òṣèrébìnrin ti orílè-èdè Nàìjíríà. Ó ti ṣàfihàn nínú àwọn fíìmù bí i The Figurine, Tinsel àti MTV Shuga.
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Funlola jẹ́ ọmọ àbígbẹ̀yìn àwọn òbí ọlọ́mọ méje. Ìyá rè jẹ́ onísòwò, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ olùdókòwò. Orúkọ FAR tí wọ́n ń pè é mọ́ ọn lórí nígbà tí ó ṣe ìgbéyàwó. FAR tètè farahàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán pẹ̀lú àǹtí rẹ̀ Teni Aofiyebi, tó jẹ́ àgbà òṣèré.[1] Ó fẹ́ olùṣèpolówó ọjà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olayinka Raimi. Látàrí ikú ẹ̀gbọ́n rè, ó pinnu láti yẹra fún ẹ̀rọ-ayélujára fún ìgbà díẹ̀, ó sì padà.[2]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Figurine (2009)
- Tinsel (2008–títí di báyìí)
- Grey Dawn (film) (2015)
- Entreat (2016)
- Walking with Shadows[3] (2019)
Awards
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|
2010 | Africa Movie Academy Awards (AMAA) | Best Actress in a Supporting Role (Figurine) | Wọ́n pèé | |
Nigeria Entertainment Awards | Best Actress in a TV Show (Tinsel) | Wọ́n pèé | ||
2017 | Best of Nollywood Awards | Best Supporting Actress –English | Wọ́n pèé | [4] |
2018 | Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead Role - English | Wọ́n pèé | [5] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Suleiman, Yemisi (30 August 2009). "I've always wanted to educate and entertain people - Funlola Aofiyebi-Raimi". Vanguard. Retrieved 29 September 2013.
- ↑ "Actress Funlola aofiyebi-Raimi returns to social media after 3-month break to mourn late brother". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2 August 2021. Retrieved 22 July 2022.
- ↑ O'Kelly, Aoife (9 October 2019). "Walking with Shadows". Oya Media. Retrieved 23 May 2021.
- ↑ "BON Awards 2017: Kannywood’s Ali Nuhu receives Special Recognition Award". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 November 2017. Retrieved 7 October 2021.
- ↑ "BON Awards 2018: Mercy Aigbe, Tana Adelana shine at 10th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 December 2018. Retrieved 23 December 2019.