Kunle Remi
Ìrísí
Kunle Remi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Òyekúnlé Ọpẹ́yẹmí Ọlúwarẹ̀mí 18 Oṣù Kẹ̀wá 1988 Gboko, Benue, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Kunle Rhemmy Teslim Terdo KR |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Fáṣítì Ìbàdàn New York Film Academy |
Iṣẹ́ | Ọ̀ṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010 – Present |
Kúnlé Rẹ̀mí (Wọ́n bi ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹwàá, ọdún 1988 | Orúkọ ìbí- Oyèkúnlé Ọpẹ́yẹmí Olúwarẹ̀mí) jẹ́ Òṣèré Nàìjíríà , tí wọ́n mọ̀ ọ́ fún àwọn ipa ribiribi rẹ̀ ní Falling,[1] Family ForeverÀdàkọ:Cn and Tinsel. Ó di olókìkí lẹ́hìn ìgbà tí ó borí ìgbà kéjẹ tí wọ́n ṣe Gulder Ultimate Search ní ọdún 2010.[2] Ó parí láti New York Film Academy.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ ""Falling" to Premiere Tomorrow with Adesua Etomi, Blossom Chukwujekwu & Kunle Remi". BellaNaija.
- ↑ "Kunle is the Ultimate Man". Vanguard Newspaper.
- ↑ "8 Nigerian entertainers who went to New York Film Academy". Goldmyne TV. Archived from the original on 2019-06-10. Retrieved 2022-02-24.