Jump to content

Kalu Ikeagwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Kalu Ikeagwu
Kalu Ikeagwu at AMA Award 21
Ọjọ́ìbíKalu Egbui Ikeagwu
18 May[1]
England[1]
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2005–present
Gbajúmọ̀ fún30 Days, Domino, Accident, Broken, Damage, Two Brides and a Baby
TelevisionTinsel, Domino, 168, Doctors' Quarters

Kalu Egbui Ikeagwu jẹ́ òṣèrékùnrin àti òǹkọ̀wé ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó sì tún tan mọ́ orílẹ̀-èdè Britain.[2] Gẹ́gẹ́ bí òṣèrékùnrin tó jẹ́, ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, wọ́n sì ti gbà á fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ pẹ̀lú fún àwọn iṣẹ́ rẹ̀.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìlú England ni wọ́n bí Kalu sí, àmọ́ ó kó lọ sí ilẹ̀ Nàìjíríà padà, nígba tó wà ní ọmọdún mẹ́sàn-án, nítorí ẹ̀rù àwọn òbí rẹ̀ pé ó lè gbàgbé àṣà àti ìṣe ilẹ̀ Igbo.[3][1] Ó ṣe ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní England àti Zambia, kí ó tó lọ sí University of Nigeria láti lọ gba ẹ̀kọ́ nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì.[3][4]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ikeagwu ṣe àfihàn àkọ́kọ́ ní ọdún 2005, nínú fíìmù àgbéléwò tí wọ́n máa ń ṣàfihàn lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Domino.[5] Ìsàfihàn akọ́kọ́ rẹ̀ lórí orí-ìtàgé jẹ́ Put Out The Houselights láti ọwọ́ Esiaba Ironsi. Ó ti tẹ̀síwájú láti lọ kópa nínú àwọn eré bí i "Major Lejoka Brown" nínú fíìmù Ola Rotimi, Our Husband Has Gone Mad Again àti gẹ́gẹ́ bí i "RIP" nínú fíìmù Esiaba Irobi, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Hangmen Also Die. Ó sì tún ti kópa nínú àwọn fíìmù bí i For Real, 30 Days, The Wrong Woman, Distance Between, Between Two Worlds àti "Rapt In Éire". Ní orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán, ó ti ṣàfihàn nínú àwọn fíìmù bí i Domino, 168 àti Doctors' Quarters (MNet Production ). Ó tún gbajúmọ̀ fún ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe gẹ́gẹ́ bí i "Alahji Abubakar" nínú fíìmù Tinsel.[6]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Second Chances(2014) as Osagie
  • Kafa Coh
  • 30 Days
  • The Distance Between
  • Between Two Worlds
  • Love my way
  • The Wrong Woman
  • Fragile Pain
  • For Real
  • Games Men Play
  • Insecurity
  • Crisis In Paradise
  • War Without End
  • My Precious Son
  • Beneath Her Veil
  • Damage
  • Daniel's Destiny Plan
  • Lionheart
  • Pretty Angels
  • The Lost Maiden
  • Darkest Night
  • Freedom Bank
  • The Waiting Years
  • Ocean Deep
  • Count On Me
  • Two Brides and a Baby
  • Broken (2013)
  • Accident
  • Blue Flames (2014)
  • Heaven's Hell (2015)
  • O-Town (film) (2015)
  • My rich boyfriend
  • Three Thieves (2015)
  • The Women (2018)
  • Badamasi (2020)

Àtòjọ àwon fíìmù rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀í Èsì Ìtọ́ka
2014 Best of Nollywood Awards Best Supporting actor Wọ́n pèé [7]
Golden Icons Academy Movie Awards Best Actor Wọ́n pèé [8]
2013 Golden Icons Academy Movie Awards Wọ́n pèé [9]
Africa Magic Viewers Choice Awards Best Supporting Actor Wọ́n pèé [10]
2012 Ghana Movie Awards Best Actor (African Collaboration) Wọ́n pèé [11]
2011 Best of Nollywood Awards Best Supporting Actor Wọ́n pèé [12]
2006 Africa Movie Academy Awards Best Upcoming Actor Wọ́n pèé

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 1.2 "Kalu Ikeagwu Biography". gistus.com. Retrieved 21 September 2014. 
  2. "Exclusive Interview with Nollywood Star Actor, Kalu Ikeagwu". modernghana.com. Retrieved 21 September 2014. 
  3. 3.0 3.1 "At age ten, I had lived in four different countries – Kalu Ikeagwu". vanguardngr.com. Retrieved 21 September 2014. 
  4. "Girls pester me for marriage, but… – Kalu Ikeagwu". My Daily Newswatch. 10 August 2013. Archived from the original on 30 September 2013. Retrieved 30 September 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named van2
  6. "Kalu Ikeagwu: Top 5 movies of the talented 'Tinsel' actor". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 20 July 2015. Retrieved 18 May 2015. 
  7. "Best Of Nollywood Awards Nominees For The Year 2014 | Jaguda.com". Archived from the original on 3 July 2015. Retrieved 6 September 2015. 
  8. "List of Nominees: Golden Icons Academy Movie Awards | Nollywood by Mindspace". Retrieved 6 September 2015. 
  9. "Ini Edo, Ramsey Nouah, “Phone Swap”, Omawumi, “Contract”, Ireti Doyle & Hlomla Dandala Make the 2013 GIAMA Nominees List | See Who Else Made the List". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015. 
  10. "Genevieve Nnaji, OC Ukeje, Funke Akindele & Kalu Ikeagwu Make the 2013 Africa Magic Viewers’ Choice Awards Nominees List | First Photos from the Announcement in Lagos". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015. 
  11. "Ghana Movie Awards: List of Nominees". Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 6 September 2015. 
  12. "The 2011 Best Of Nollywood (BON) Awards hosted by Ini Edo & Tee-A – Nominees List & “Best Kiss” Special Award". BellaNaija. Retrieved 6 September 2015.