Tonto Dikeh
Tonto Dikeh | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Tonto Charity Dikeh 9 Oṣù Kẹfà 1985 Port Harcourt, Rivers, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn |
|
Iléẹ̀kọ́ gíga | Rivers State University of Science and Technology |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 2006–present |
Notable work |
|
Olólùfẹ́ | Oladunni Churchill (m. 2015; div. 2017) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Musical career | |
Irú orin |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2011–2017 |
Labels | Poko Entertainment |
Associated acts |
|
Website | tontodikehent.com |
Tonto Charity Dikeh (bìì ńì ọ̀jọ́ kẹ́sáń òṣùkèjé ọ̀dùń1985) jẹ́ òlòrìń[1] átì òṣèré òrìlẹ́- édé Náìjírìá.[2][3] Ńì ọ̀jọ̀ kẹ́tádìlọ̀gbọ̀ń òṣù kẹ́jọ̀ ọ̀dùń 2000, Tonto Dikeh dá ẹ́gbẹ́ rẹ́ kàlẹ́ èyì tì ò pè ńì "The Tonto Dikeh Foundation". Ẹ́gbẹ́ ńáà wá látì pèsé ìgbè àìyè tò rọ̀rùń fùń àwọ̀ń òbìńrìń , ọdọ,ọ̀mọ̀dèbìńrìń átí awọ̀ń ọ̀mọ̀dè ńì ílẹ́ Áfrìká ni ile Áfrìká nipa ẹ́sìń ika ẹ́gbẹ́ òṣèlù tabi ẹ́yá wọ̀ń. [4]
Ni osu kefà odún 2022,ni won yan Tonto Dikeh gege bi oludije fun igbakeji gomina ìpínlè Rivers ti odun 2023 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú African Democratic Congress.[5][6]
Áwọ̀ń Èrè órì rè tágè rẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ̀ń ṣè áfìháń Tonto Dikeh lórì èrè òrì tágè káń tì ákọ̀lè eẹ́ jẹ́ "Dirty Secret " , tì ò pádá dì òhùń tì áwọ̀ń ẹ́yáń sọ̀ ńìpá ípá tì Tonto Dikeh kò ńì pá ẹ́, tì wọ̀ń ṣì sọ̀pè Tonto Dikeh kò pá ńìńù èré bì agbalagba. Awọ̀ń kan si sọ̀pè nipa ti ò Ko yẹ́ń, Ko wu wa bi awọ̀ń ọ̀mọ̀ Ileẹ́ Áfrìká.Bẹ́ sìńì okan ṣè ìṣẹ́ rẹ̀ ńì [3][4].
Íṣẹ́ òrìń ẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ńì ìgbá tì Tonto Dìkèh ṣè áṣè yọ̀rì ńìńù íṣè òṣèré òtèsìwájù látì bẹ́rẹ̀ ìṣẹ́ òrìń. Kòtò dìgbá ńá wọ̀ńtì fì háń ńìńù órìń káń tì Patience Ozokwor wá ńìbẹ́, tìtì Amaco investment [5] Òrìń ákọ̀kọ̀ tì òkọ̀kọ̀gbèjádè ńì "Hi atì Its Ova", lẹ́yìń gbáńà ńì wọ̀ń tì ṣè áfìháń rẹ́ ńìńù òrìń káń tì ákọ̀lè rè jẹ́ "Snypa" [6] [7] .Ńì ọ̀jọ̀kẹ́tálá òṣù kẹ́fá ọ̀dùń 2014,Dbanj gbá wòlè sìńù labelì ẹ́ tì wọ̀ń pè ńì ,DB Records.[8] Tonto Dikeh ṣè ìkèdè bì òṣè kùrò ńìńù làbelì Dbanj ńì òṣù kẹ́tá ọ̀dùń 2015.[9]
Ígbèsì áyè átì ẹ́kọ̀ rẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wòń bì Tonto Dikeh sì ńù ẹ́bì mèjè tì ò sì ṣè ọ̀mọ̀ kẹ́tá Ninu awọ̀ń márùń . Áwọ̀ń ẹ́bì ẹ́ wá látì ìlù Obio-Akpor, Ti ò jẹ́ ìbìlẹ́ kan si ìpìńlẹ́ Rivers , osì wá látì íráń Ikwerre .[10][11][12] Ńì Ìgbá tì ò di odun mẹ́tá, ò pádáńù Íyá rẹ́ tì ìyáwò bábá rẹ́ tì ò bì ọ̀mọ̀ mèjì tì ò sì gbá tọ̀. .[13] Dikeh ká petrochemical engineering ńì fásìtí Ìpìńlẹ́ Rivers tì ìmọ̀ Science átì Technology.[14] Òṣè ìgbèyáwò pẹ́lù Oladunni Churchill tì ò ṣè ńì òṣù kẹ́jọ̀ ọ̀dùń 2015. Ńì ọ̀dùń 2016 ọ̀ṣù kèjì òbì ọ̀mọ̀ ọ̀kùńrìń tì ìńàgìjẹ́ rẹ́ jẹ́ Baby X.[15] Látì ìgbá ńá ńì àwọ̀ń ọ̀kọ̀ átì Ìyáwò tì lọ̀ lọ̀tọ̀tọ̀.[16]
Ńì ọ̀jọ̀ Òkáńlèlọ̀gbọ̀ń òṣù kèjè ọ̀dùń 2020, Tonto Dikeh kò sì ẹ́rò àiyè lùjára (Instagram) látì ṣè ájọ̀ yọ̀ pẹ́lù ọ̀rẹ́ rẹ́ Bobrisky .[17]
Endorsement
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ńì ọ̀jọ̀ kárùń òṣù kèjì ọ̀dùń 2016,Dikeh jẹ́ ambassador fun ile ìṣẹ́ kan ti òńjẹ́ (NUMATVILLE)Ni òlùlù Ńájìrìá (Abuja) tì property ná tò miliion pùpọ̀.[18]
Ńì ọ̀dùń kẹ́sáń òṣù kìńì ọ̀dùń 2018, Dikeh jẹ́ Ambassador fùń ìlè ìṣẹ́ ògè tì òrùkọ̀ rẹ́ jẹ́ (Pels International) tì ìlè ìṣẹ́ yì jẹ́ ọ̀hùń tì wọ̀ń mọ̀ kákìrì ágbálàyè. .[19]
Ńì ọ̀dùń 2018,ọ̀jọ̀ kẹ́jọ̀ òṣù kẹ́tá ,Dikeh jẹ́ Ambassador fùń "Sapphire Scents" ìlè ìṣè Ńáfìńdá ńì ìlẹ́ Ńáìjìrìá. [20]
Ńì òjọ̀ kẹ́tádìńlọ̀gbọ̀ń ,òṣù kẹ́rìń ọ̀dùń 2018,Dikeh jè Ambassador tì ájọ̀ tò bòjùmọ̀ ìmá kò àwọ̀ń èyáń lẹ́rù( National Agency For Prohibition of Trafficking In Persons) NAPTIP).[21]
Ńì ọ̀dùń 2019,Òṣù kẹ́tá ọ̀jọ̀ kẹ́rìńlèlògùń, ò dì ambassador fùń ìlè ìṣẹ́ Amstel Malta.[22]
Ńì ọ̀dùń 2019,òsù kárùń ọ̀jọ̀kètálèlogùń ,Dikeh tọ̀wọ̀bọ̀ endorsiment fùń ìlè ìṣẹ́ Zikel Cosmetics.[23]
Àwọ̀ń òrìń tì ò dáṣè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ákọ̀lè átì ọ̀dùń tì ò ṣè
"Hi" 2012
"Itz Ova"
"Crazically Fit" (featuring Terry G)
"Jeje" 2013
"Sheba" (featuring Solid Star)
"Ekebe" 2014
"Sugar Rush" (featuring D'banj) 2015
Awọ̀ń èré òrìtágè tì ò kò pá ńìńù ẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tea or Coffee (2006)
Pounds and Dollars (2006)
Missing Rib (2007)
Final Hour (2007)
Divine Grace (2007)
7 Graves (2007)
Crisis in Paradise (2007)
Insecurity (2007)
Away Match (2007)
Games Fools Play (2007)
The Plain Truth (2008)
Love my Way (2008)
Before the Fall (2008)
Total Love (2008)
Strength to Strength (2008)
Missing Child (2009)
Native Son (2009)
Dangerous Beauty (2009)
My Fantasy (2010)
Zara
Dirty Secret (2010)
Last Mission
Blackberry Babes Re-loaded (2012)
Secret Mission
Rush Hour
Fatal Mistake
Family Disgrace
Miss Maradonna
Mortal Desire
Criminal Widow 1
Criminal Widow 2 (2013)
Then Terror of a Widow 1 (2013)
Then Terror of a Widow 2 (2013)
Battle of the Queens (2014)
Throne of War (2014)
Awọ̀ń íwè áṣáyáń itọ̀kásì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]1.ABOUT TONTO DIKEH". Archived from the original on 28 June 2016. Retrieved 20 February 2019.
2. ^ "Tonto DIkeh Foundation". today.ng. today.ng. 2 June 2020. Retrieved 2 June 2020.
3.^ "Nigeria: Nollywood Splits Over Tonto Dike". allAfrica.com. Retrieved 4 February 2011.
4.^ "Nigerian celebrities and Tattooing". The Vanguard. Lagos, Nigeria. 6 January 2012. Retrieved 15 January 2012.
5. ^ "Tonto Dikeh life history and profile, Playing music with Patience Ozokwor". Anambra fashion week. 22 January 2012.
6.^ "World Premiere Tonto Dikeh". Too Xclusive.
7.^ "Tonto Dike needs to learn how to sing". Nigeria films.
8.^ "D'banj Finally Unveils DB Records Lee Family". Joints Arena.
9.^ "Tonto Dike Leaves D'banj's Record Label". Naija Loaded.
10.^ "Olakunle Churchill sues ex-wife Tonto Dikeh, demands N500 million". Gistflare.com.ng – Nigeria news. Retrieved 9 February 2019.
11.^ "Tonto Dikeh". Naij.com – Nigeria news. Retrieved 9 February 2017.
12.^ "Actress Tonto Dikeh Full Biography Life And News – How Nigeria". How Nigeria. 29 September 2015. Retrieved 9 February 2017.
13.^ "Photos – Tonto Dikeh Shares Late Mum, Step Mother & Dad". MJ Celebrity Magazine. Retrieved 24 October 2016..
14.^ "Tonto Dikeh Biography,Life History,Profile & movies". NaijaGists.com. Retrieved 24 October 2016..
15.^ "Actress welcomes first child, releases maternity photos". Pulse Nigeria. 18 February 2016. Retrieved 7 April 2019.
16.^ "Actress reveals sadness over her relationship with husband, Churchill, in an interview with OAP Daddy Freeze". TonyGutsy. 28 April 2019. Retrieved 7 May 2019.
17.^ "Tonto Dikeh Celebrates Best Friend, Bobrisky On His Birthday". The African Media. 31 August 2020. Retrieved 31 August 2020.
18.^ "Property firm appoints Tonto Dikeh as brand ambassador". Inemesit Udodiong. 24 May 2020. Retrieved 24 May 2020.
19.^ "Tonto Dikeh Gets Endorsement Deal With Beauty Brand". mystatenews. mystatenews. 24 May 2020. Retrieved 24 May 2020.
20.^ "Tonto Dikeh Becomes Sapphire Scents Brand Ambassador". Naija Gists. 24 May 2020. Retrieved 24 May 2020.
21.^ "Tonto Dikeh bags endorsement deal". Kemifilani. Kemifilani. 24 May 2020. Retrieved 24 May 2020.
22.^ "Tonto Dikeh Revealed As Amstel Malta New Brand Ambassador". Plat4om. Plat4om. 1 August 2019. Retrieved 1 August 2019.
23.^ "Tonto Dikeh bags N100m deal with Zikel cosmetics". Oak TV Newstrack. Oak Tv. 23 May 2019. Retrieved 25 June 2019.
24.^ "Tonto Dikeh – Itz Ova + Hi". 17 October 2012.
25.^ "Single Premiere: Tonto Dikeh ft Terry G - Crazically Fit - 360Nobs.com".
26.^ "Tonto Dikeh – JEJE". 28 February 2013.
27.^ "Tonto Dikeh – Sheba ft Solidstar". 9 June 2013.
28.^ "Tonto Dikeh premieres New Song "Ekebe" – Listen".
29. ^ "VIDEO: Tonto Dikeh – Sugar Rush ft. D'banj". 28 April 2015.
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Tonto Dikeh life history and profile, Playing music with Patience Ozokwor". Anambra fashion week. 22 January 2012. Archived from the original on 9 March 2015. Retrieved 11 October 2020.
- ↑ "Those linking Tonto Dikeh to my house demolition are liars –Ex-lover Kpokpogri". Punch Newspapers. May 21, 2022. Retrieved May 29, 2022.
- ↑ "ABOUT TONTO DIKEH". Archived from the original on 28 June 2016. Retrieved 20 February 2019.
- ↑ "Tonto DIkeh Foundation". today.ng. today.ng. 2 June 2020. https://www.today.ng/topic/tonto-dikeh-foundation. Retrieved 2 June 2020.
- ↑ "ADC Nominates Tonto Dikeh As Deputy Governorship Candidate For Rivers". Channels Television. June 24, 2022. Retrieved June 25, 2022.
- ↑ Ogala, George (June 24, 2022). "Tonto Dikeh emerges running mate to Rivers ADC governorship candidate". Premium Times Nigeria - Premium Times - Nigeria's leading online newspaper, delivering breaking news and deep investigative reports from Nigeria. Retrieved June 25, 2022.
- ↑ "Olakunle Churchill sues ex-wife Tonto Dikeh, demands N500 million". Gistflare.com.ng – Nigeria news.. https://gistflare.com.ng/olakunle-churchill/.
- ↑ "Tonto Dikeh". Naij.com – Nigeria news.. https://www.naij.com/tag/tonto_dikeh.html.
- ↑ "Actress Tonto Dikeh Full Biography Life And News – How Nigeria". How Nigeria. 29 September 2015. Archived from the original on 1 May 2017. https://web.archive.org/web/20170501220128/http://howng.com/actress-tonto-dikeh-full-biography-life-and-news/.
- ↑ "Photos – Tonto Dikeh Shares Late Mum, Step Mother & Dad". MJ Celebrity Magazine. Archived from the original on 19 January 2017. Retrieved 24 October 2016..
- ↑ "Tonto Dikeh Biography,Life History,Profile & movies". NaijaGists.com. Retrieved 24 October 2016..
- ↑ "Tonto Dike Leaves D’banj's Record Label". Naija Loaded.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from September 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1985
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn òṣeré ará Nàìjíríà