Okechukwu Oku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Okechukwu Oku
Ọjọ́ìbíOkechukwu Oku
Enugu, Enugu State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànOkey Oku, the Oracle
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Film producer, director, cinematographer
Ìgbà iṣẹ́2001 – present
Notable workBambitious
Olólùfẹ́Queendalyn Oku
Àwọn ọmọ3

Okechukwu Oku /θj/, tí ayé mọ̀ sí Okey Oku tàbí Oracle jẹ́ Olùdarí, olùṣe, cinematographer àti ọ̀kọọri. [1] ó Di gbajúmọ̀ látàrí fíìmù tí ó darí rẹ tí àkọlé rẹ ń jẹ́ Love and Oil tó jáde ní ọdún 2014, Burning Bridges ní ọdún 2014) àti Bambitious[2] (2014) tí àwọn Òṣeré bí Belinda Effah àti Daniel K Daniel náà kópa nínú eré náà.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oku jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlè Enugu ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí ó sì jẹ́ ọmọ tí wọ́n bí sì kejì nínú ọmọ mọ́kànlá tí àwọn òbí rẹ̀ Goddy àti Winifred Òkú bí. [3] Ó jẹ́ ọmọ íbò tí ó wá láti Ukpo ni agbègbè Dunukofia ni ìpínlè Anambra. [4] Baba rẹ̀, Goddy ńnẹ́ Gbajú-gbaà Olórin ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ní ọdún 1970s, tí ìyà rẹ̀ Wínifred sì jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba tí ó ti fẹ̀yìntì. Ẹ̀gbọ́n Oku, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Udoka (Selebobo) Oku jẹ́ ẹni tí ó máa ń gbé orin jáde àti ọ̀kọọri. [5]

Oku bẹ̀rẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ ni ilẹé ẹ̀kọ́ kékeré WT ni Enugu, tí ó sì tẹ síwájú láti lọ sí St. Charles Special Science School ni Onitsha, ní ìpínlè Anambra. Ní àárín kíkọ́ ẹ̀kọ́ àti lílọ sì ilé ìwé gíga Fáṣítì, oku sọ pé òun fẹ fi ìwé lè láti ṣíṣẹ Theatre. Nibẹ ni Oku tí bẹ̀rẹ̀ si nífẹ̀ẹ́ sì iṣẹ́ orin, tí ó sì kọ àwọn orin kììtẹ́nì[6] tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe orin Jáde fún àwọn olórin ni gúúsù ìlà oòrùn ni orílè èdè Nàìjíríà,[7] Nípa báyìí ni ó padà di ẹni tí ó ń darí fídíò fún tẹlifíṣàn.

Ìgbé Ayé[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oku ṣe ìgbéyàwó p pẹ̀lú Queendalyn OKu[8] Wọ́n sì bí ọmọ Mẹ́ta, tí Wọ́n sì ń gbé ní Enugu ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Àwọn Eré tí ó Kópa níbẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Feature Films

Year Title Major Cast Role Notes
2012 Brother's Keeper Omoni Oboli, Beverly Naya, Majid Michel, Barbara Soki Cinematographer, Editor Feature Film, nominated for the 2014 Nollywood Movies Awards for Best Editing and also for the 2013 Golden Icons Academy Movie Awards for Best Cinematography
2012 Last 3 Digits Nonso Diobi, Sidney "Dr. Sid" Esiri, Yomi Blaq, Rachel Oniga Director of Photography Feature Film, won Best International Film Award
2013 Finding Mercy Rita Dominic, Blossom Chukwujekwu, Chioma Akpotha Director of Photography Feature Film, Africa Movie Academy Award - Best Actor, Nollywood Movie Award - Best Rising Star, Nigerian Entertainment Award - Best Supporting Actor
2014 Love and Oil Yul Edochie, Nuella Njubigbo, Jibola Dabo, Chinaza Ekezie Director Feature Film
2014 Burning Bridges Ivie Okujaye, Ken Erics, Esther Audu Director Feature Film
2014 Bambitious[9] Belinda Effah, Bucci Franklin, Daniel K Daniel, Ebele Okaro-Onyiuke Director, Cinematographer, Editor Feature Film, won multiple awards at the AAFMF
2014 Refugees Yvonne Nelson, Belinda Effah, Diana Yekinni, Sandra Don Dufe, Ross Fleming, David Chin Cinematographer Feature Film, nominated for Best Cinematography at the 2016 AMVCA
2014 Chetanna Chigozie Atuanya, Queen Nwokoye DP, Editor Feature Film, nominated for Best Igbo Film at the 2014 AMVCA and won GIAMA Awards for Best Indigenous Film
2016 Blackrose Blossom Chukwujekwu, Ebele Okaro-Onyiuke, Lilian Echelon, Betty Bellor, William Iruoha (2Shotz) Director Feature Film
2016 A Better Family Frederick Leonard, IK Ogbonna Director, DP, Editor Feature Film, released on YouTube
2016 Excess Luggage IK Ogbonna, Mike Ezuronye, Queen Nwokoye DP, Editor Feature Film, nominated for the BON Awards for Best Comedy and a Toronto Film Festival Official Selection
2016 Jofran IK Ogbonna, Lisa Omorodion Producer, Director, DP, Editor Feature Film, Africa Magic Original Film
2016 Let's hit the Streets Alex Ekubo, IK Ogbonna Director, DP, Editor Feature Film
2016 Tommy and Kenny Belinda Effah, Buchi Franklin Director, DP, Editor Feature Film
2017 Dirty Laundry Zach Orji, Kalu Ikeagu Proucer, Director, DP, Editor Feature Film, Africa Magic Original Film
2017 American Driver Evan King, Jim Iyke, Anita Chris, Nse Ikpe Etim, Nadia Buari, Emma Nyra, Ayo Makun, Laura Heuston, McPc the Comedian, Michael Tula, Andie Raven Cinematographer Feature Film, won Best Comedy at The People's Film Festival in 2017
2017 Sarah's Epiphany Daniella Okeke, Mike Ezuruonye, Anthony Monjaro Director Feature Film
2017 Levi Ramsey Nouah, Nancy Isime, Deyemi Okanlawon Director/Producer/Editor Feature Film

Music Videos

Ìgbórínyìn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Year Award Category Film Result
2013 2013 Golden Icons Academy Movie Awards Best Cinematography Brother's Keeper Wọ́n pèé
2014 2014 Nollywood Movies Awards Best Editing Brother's Keeper Wọ́n pèé
2015 Afrifimo Awards and Film /Music Festival[11] Best Film Director Bambitious Gbàá
2016 Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA)[12] Best Cinematographer for a Movie or TV Series Refugees Wọ́n pèé
2018 Zulu African Film Academy Awards (ZAFAA)[13] Best Film Editor Black Rose Gbàá

Ẹ tún lè wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Okechukwu Oku Archives". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-30. 
  2. Nwaebele, Emeka (25 November 2014). "BAMBITIOUS: FIRST EVER MOVIE TO BE PREMIERED IN ENUGU". Nigeriafilms.com (Lagos, Nigeria). http://www.nigeriafilms.com/news/30215/45/bambitious-first-ever-movie-to-be-premiered-in-enu.html. Retrieved 7 December 2015. 
  3. TECH. "Okechukwu Oku: Biography". imdb.com. United States. Retrieved 7 December 2015. 
  4. Nwadike, Chinedu (4 July 2015). "Selebobo's Elder Brother Okey Oku (TheOracle) Nominated for best director at the AAFMF Awards". otowngist.com (Enugu, Nigeria). Archived from the original on 6 March 2017. https://web.archive.org/web/20170306055655/http://www.otowngist.com/index.php/others/audio-video/4025-selebobo-s-brother-okey-oku-nominated-for-best-director-at-the-aafmf-awards.html. Retrieved 21 December 2015. 
  5. S, Kay (25 July 2015). "Selebobo's Elder Brother Okey Oku (TheOracle) Nominated for best director at the AAFMF Awards". KorrectNaija.com (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 22 December 2015. https://web.archive.org/web/20151222144942/http://www.korrectnaija.com/2015/07/selebobos-elder-brother-okey-oku.html. Retrieved 7 December 2015. 
  6. Jojo, Olia (10 December 2011). "FRESH XMAS MUSIC: OKEY OKU - SILENT NIGHT". justjojoentertainment.com (Enugu, Nigeria). http://www.justjojoentertainment.com/members-area/artist-bloggers/entry/2011/12/10/fresh-xmas-music-okey-oku-silent-night. Retrieved 21 December 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. Aniocha, Emeka (9 December 2011). "New Music: The Oracle a.k.a Okey Oku - Silent Night". IgboKwenuRadio.com (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 22 December 2015. https://web.archive.org/web/20151222135406/http://igbokwenuradio.com/new-music-the-oracle-a-k-a-okey-oku-silent-night/. Retrieved 21 December 2015. 
  8. Blaise, Julia (26 July 2015). "CEO Oracle Films, Okechukwu Oku Dedicates Son". JuliaBlaise.com (Lagos, Nigeria). http://www.juliablaise.com/2015/07/photos-ceo-oracle-films-okechukwu-oku.html. Retrieved 9 December 2015. 
  9. Izuzu, Chidumga (2 December 2014). "Bambitious: Daniel K Daniel, Belinda Effah, Selebobo attend Enugu premiere". Pulse Nigeria (Lagos, Nigeria). http://pulse.ng/movies/bambitious-daniel-k-daniel-belinda-effah-selebobo-attend-enugu-premiere-id3316740.html. Retrieved 9 December 2015. 
  10. Ayeni, Kunle (3 July 2013). "VIDEO: Flavour – 'Ada ada'". TheNETng (Lagos, Nigeria). http://thenet.ng/2013/07/video-flavour-ada-ada/. Retrieved 21 December 2015. 
  11. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AAFMF
  12. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AMVCA
  13. "ZAFAA Global Award 2018 – the Complete Winners List | African Glitz Magazine". Archived from the original on 2023-10-10. Retrieved 2023-10-09.