Regina Daniels

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Regina Daniels
Ọjọ́ìbí Regina Daniels
10 Oṣù Kẹ̀wá 2000 (2000-10-10) (ọmọ ọdún 19)
Nigeria
Orílẹ̀-èdè Nigerian
Ẹ̀kọ́ Igbinedion University
Iṣẹ́ Actress/producer
Parent(s) Rita Daniels

Regina Daniels tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 2000 (October 10th, 2000) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] [2][3][4][5]

Ìgbé-ayé àti ẹ̀kọ́ kíkà rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Regina kàwé ní Hollywood International School[6] bẹ́ẹ̀ náà ló kàwé gboyè nínú ìmọ̀ iṣẹ́ ìbánisọ̀rọ̀ Mass Communication lọ́dún 2018 [7] ní ifáfitì Igbinedion University.[8][9]

Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Regina Daniels jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò lédè Gẹ̀ẹ́sì. Àwọn wọ̀nyí ni díè nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

 • Dumebi in School
 • Python Girl
 • The Bat-Man
 • The Jericho
 • Plantain Girl
 • Jaja the Great
 • The Jericho (as producer)
 • Twins Apart (as producer)
 • Tears of Ojiugo
 • Wipe your Sorrows
 • Royal Covenant
 • Traditional War (Part 1)
 • Stronger Than the Gods
 • The King and The Python
 • Hanging Coffin
 • Evil messenger 1 and 2
 • Queen Rebeca

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Techbuddie (2017-10-10). "Actress Regina Daniels Celebrates 17th Birthday With Lovely Photos". National Mirror Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-05-07. 
 2. "10 Things You Need To Know About 21-Year-Old Nollywood Actress, Regina Daniels" (in en-US). Nigerian Celebrity News + Latest Entertainment News. 2016-12-29. http://stargist.com/nigerian_celebrity/about-regina-daniels-regina-daniels-biography-regina-daniels-profile-regina-daniels-wikipedia/. 
 3. admin (July 23, 2016). "Regina Daniels: As a 17-year-old Actress, I Earned N500,000 for a Role". 
 4. Deolu (2016-07-23). "Regina Daniels: As A 14 Year-Old Actress, I Earned N500,000 For A Role". INFORMATION NIGERIA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-05-07. 
 5. "Teen Actress, Regina Daniels flaunts hot body on election day after being disqualified by age". Within Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-24. Retrieved 2019-05-07. 
 6. Ibenegbu, George (2018-02-22). "Top 5 facts from ☀ Regina Daniels' biography you should know" (in en-US). Naija.ng – Nigeria news.. https://www.naija.ng/1100121-regina-daniels-nigerian-actress-biography.html#1100121. 
 7. Oladimeji (2017-11-08). "Regina Daniels Attends Igbinedion University, Shocking Revelations About Her Education Life | 36NG" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-30. 
 8. "Teen Actress Regina Daniels Bags Igbinedion University Award". Eagle Online. Retrieved 2018-08-01. 
 9. "Regina Daniels Attends Igbinedion University, Shocking Revelations About Her Education Life". Retrieved 2018-08-01.