Nnamdi Azikiwe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Àdàkọ:Infobox Aarẹ

Nnamdi Azikiwe

Benjamin Nnamdi Azikiwe (November 16, 1904May 11, 1996) tabi Zik jẹ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, láti ẹ̀yà Igbo. Ọkan ninu awon ólósèlú pàtàkì ni Azikiwe jẹ ni Nàìjíríà, o si jẹ asíwájú fun Ifegbega orile-ede ara ẹni ni Nàìjíríà lodeoni, bẹ sini o tun jẹ Aare ile Naijiria akọkọ ni Ìgbà Òṣèlú Àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà leyin igbati Nàìjíríà gba ominira ni odun 1960.

Ìgbà èwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Azikiwe ní ojo 16 osu kokanla ọdún 1904 ni Zungeru, ni apa ariwa Naijiria botile jepe awon obi re je Ígbò lati apa ilaoorun Naijiria.[1] Nnamdi tumosi "baba mi wa laaye."[2] Leyin eko re Methodist High School ni Èkó o gbera lo si ile Amerika. Nibe o ka we ni Yunifasiti Howard ni Washington, D.C.[3] ko to di pe o pari eko re ni Yunifasiti Lincoln ni Ipinle Penssylvania ni 1930. Ó kàwé ní calabar àti Èkó. Òun ni olóòtu, Morning Post West African Pilot. Ó di ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ tí yóò je Gomina-Gbogbogbo fun Nigeria ní 1960. Ó se ìdásílè University of Nsukka. Ó kú ní odún 1996.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nnamdi Azikiwe". Encyclopædia Britannica Online. Encyclopædia Britannica, Inc. Retrieved 2007-05-03. 
  2. Madubuike, Ihechukwu (1976). A Handbook of African Names. Three Continents Press. p. 219. ISBN 0914478133. 
  3. "Biography of Dr. Nnamdi Azikiwe". [www.onlinenigeria.com]. Retrieved 2007-09-05.