Jump to content

Sani Abacha

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
General Sani Abacha
10th Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
17 November, 1993 – June 8, 1998
AsíwájúErnest Shonekan
Arọ́pòAbdulsalami Abubakar
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1943-09-20)Oṣù Kẹ̀sán 20, 1943
Kano, Nigeria
AláìsíJune 8, 1998(1998-06-08) (ọmọ ọdún 54)
Abuja, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúnone (military)

Sani Abacha (20 September 19438 June 1998) je Ogagun Ile-Ise Ologun ile Naijiria ati Olori orile-ede Naijiria lati ojo 17 osu Kokanla odun 1993 titi de ojo 8 osu Kefa 0dun 1998 to ku lojiji. [1][2]

Wọn bí Abacha ní ìlú Kano ni Nàìjíríà.[3] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Nigeria Military Training College tí Ìlú Kaduna Ọgbà ipò igbimọ in Ọdún 1963 leyin tí ó dé láti ikẹ eko tó cadeti ni ìlú Aldershot ni England.

Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ni ọdún 1998,abacha ku si Aṣọ Rock tí àwọn Ààrẹ ni ìlú Abuja[2].Wọn sìn Abacha ní ìlà náà tí Mùsùlùmí. Àwọn kàn ní májẹ lè ní opáa, àwọn kan ni àwọn apá yàn ni wọ́n paa, àti bẹẹbẹẹ ló ní pàtó kosi ẹni tí ó mọ ìdí ikú rẹ.Lẹ́yìn ikú rẹ, wọn fi Ọgbẹ́ni Abdulsalami Abubakar ṣe olú dárí tí ìpínlẹ́ ni Oṣù Kẹ̀wá ọdún 1998[4].