Yakubu Gowon

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Yakubu Gowon
Olori Orile-ede Naijiria 3k
In office
1 August 1966 – 29 July 1975
Vice President J.E.A Wey gegebi Chief of Staff, Supreme Headquarters
Asíwájú Johnson Aguiyi-Ironsi
Arọ́pò Murtala Mohammed
Oga Omose Agbogun
Lórí àga
January 1966 – July 1966
Asíwájú Johnson Aguiyi-Ironsi
Arọ́pò Joseph Akahan
Personal details
Ọjọ́ìbí 19 Oṣù Kẹ̀wá 1934 (1934-10-19) (ọmọ ọdún 84)
Kanke, Plateau State, Naijiria
Spouse(s) Victoria Gowon
Alma mater Royal Military Academy Sandhurst
University of Warwick
Military service
Allegiance  Nigeria
Service/branch  Adigun Nàìjíríà
Years of service 1954–1975
Rank Ogagun

Yakubu "Jack" Dan-Yumma Gowon (ojoibi 19 Oṣù Kẹ̀wá 1934) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Bàìjíríà láti apá Àríwá. Gowon jẹ́ Ọ̀gágun ní Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ni ó sì tún jẹ̀ olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ódún 1966 dé 1971. Kásìkò ìjọba rẹ̀ náà ni ilẹ̀ Nàìjíríà ja ogun abẹ́lé láti 1966 sí 1971, lábẹ́ ogágun Odumegwu Ojukwu tí ó fẹ́ gba òmìnira lọ́wọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà.


Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]