Jump to content

Ike Nwachukwu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ike Omar Sanda Nwachukwu
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ímò
In office
January 1984 – August 1985
AsíwájúSam Mbakwe
Arọ́pòAllison Madueke
Alákóso Ọ̀rọ̀ Òkèrè ilẹ̀ Nàìjíríà
In office
December 1987 – December 1989
AsíwájúBolaji Akinyemi
Arọ́pòRilwan Lukman
In office
September 1990 – January 1993
AsíwájúRilwan Lukman
Arọ́pòMatthew Mbu
Alàgbà Aṣòfin fún Imo North
In office
May 1999 – May 2003
Arọ́pòUche Chukwumerije
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹ̀sán 1941 (1941-09-01) (ọmọ ọdún 83)
Port Harcourt, Nigeria

Ike Omar Sanda Nwachukwu (ojoibi September 1, 1940)[1] jẹ́ ọmọ ológun tótifèyìntì àti olósèlú ará ilè Nàìjíríà tó di ọ̀pọ̀lọpọ̀ ipò mú ní ìjọba Nàìjírí̀a, ó di Alákòso Ọrọ òkèrè lẹ́ẹ̀mejì̀, Gómínà Ìpínlè Ímò àti Alágba nínú àwọn asojú Ilè-ìgbìmọ̀ Asòfin lati Ìpínlè Ábíá.