Jump to content

Evan Enwerem

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Evan Enwerem
Gomina Ipinle Imo
In office
1992–1993
Alagba lati Ilaorun Imo
In office
1999–2003
Arọ́pòAma Iwuagwu
ConstituencyImo-East Senatorial Zone
Aare ile Alagba Naijiria
In office
June 3, 1999 – November 18, 1999
AsíwájúAmeh Ebute
Arọ́pòChuba Okadigbo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOctober 29, 1935
Ikeduru, Imo State
AláìsíAugust 2, 2007
Abuja, Federal Capital Territory
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAPP, then PDP
Àwọn ọmọSeven
Alma materUniversity of Southampton

Evan Enwerem (October 29, 1935 - August 2, 2007) je oloselu omo ile Naijiria to je ipo Aare ile Alagba Naijiria ni 1999.[1] O je omo egbe oloselu People's Democratic Party.