Ken Nnamani
Appearance
Ken Nnamani | |
---|---|
National Senator for Enugu East | |
In office May 2003 – May 2007 | |
Asíwájú | Jim Nwobodo |
Arọ́pò | Chimaroke Nnamani |
President of the Nigerian Senate | |
In office April 2005 – May 2007 | |
Asíwájú | Adolphus Wabara |
Arọ́pò | David Mark |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kọkànlá 1948 Enugu, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
Alma mater | Ohio University |
Occupation | Businessman |
Kenneth Ugwu Nnamani je alagba asofin ile Nigeria tele to soju fun Ipinle Enugu lati 2003 de 2007. Omo egbe oloselu People's Democratic Party (PDP) loje. Ni 2005 o di Aare Ile Alagba Asofin Naijiria titi di 2007.[1]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Gbenga Oke (7 May 2008). "Ken Nnamani - Taking Good Governance and Development to Greater Height". Vanguard. Retrieved 2009-10-06.