David Brigidi
Ìrísí
David Cobbina Brigidi | |
---|---|
Aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office Oṣù karún Ọdún 1999 – Oṣù karún Ọdún 2007 | |
Arọ́pò | Emmanuel Paulker |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ìpínlẹ̀ Bayelsa |
David Cobbina Brigidi jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àárín Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 1999 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Congressional Committees". Nigeria Congress. Archived from the original on 2009-11-18. Retrieved 2010-06-24.
- ↑ "Senator Brigidi Urges Rehabilitation of Militants". Leadership. 22 July 2008. Retrieved 2010-06-24.