Jump to content

Jim Nwobodo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jim Nwobodo
Gomina Ipinle Anambra
In office
October 1979 – October 1983
AsíwájúD.S. Abubakar
Arọ́pòChristian Onoh
Alagba Asofin fun Ilaorun Enugu
In office
29 May 1999 – 29 May 2003
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíMay 9, 1940
Agyaragu, Lafia, Ipinle Nassarawa, Nigeria

James Ifeanyichukwu Nwobodo tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí (Jim Nwobodo) (ni a bí ní Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù karùn-ún ọdún 1940) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà ìgbà kan ní Ìpínlẹ̀ Anambra lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.